O lè Kẹ́kọ̀ọ́ èdè yorùbá pẹ̀lú Olùkọ́ Orlandes o sì, síwájú sí i, jẹ́ kí àwọn òrìṣà darí ẹ padà sí ìlú ìbílẹ̀ rẹ. Kí èrò inú rẹ lílágbára ṣẹ, òmìnira,
yan ohun tí ó tọ́ o sì di olórí rere - Aprenda yorubá com o professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.
Ọ̀rọ̀-ìwàláyè (ontologia) Ontologia significa “estudo do ser” e consiste em uma parte da filosofia que estuda a natureza do ser, a existência e a realidade.
Bàbá àwọn ìbáraẹnisọ̀rọ̀ ti àkókò díjítà. Pai das comunicações da era digital.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário). Bàbá, baba s. Pai, papai, mestre. Àwọn, wọn, pron. Eles, elas. Indicador de plural. Ọ̀rọ̀, s. Palavras, texto, assunto, expressão. Ìfifún, s. Doação, presente. Ìkọ̀wé, s. Escrita. Ọ̀rọ̀ìfifúnìkọ̀wé, ìbádámọ̀ràn, ìbáraẹnisọ̀rọ̀, s. Comunicação. Ìbánisọ̀rọ̀, s. Interação. Àfigbébánisọ̀rọ̀, ìgbéfibánisọ̀rọ̀, ìbánisọ̀rọ̀-ọ̀ọ́kán, s. Telecomunicação. Àkókò díjítà, s. Era digital. Ti, prep. De (indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai). Àkókò, s. Tempo, estação, época, era. Díjítà, adj. Digital. 1. Èṣù (Exú). Orixá da comunicação, dos caminhos e da fertilidade.
Ìjọba ìmúnisìn tipátipá nínú ìṣe ìránṣẹ́ ìdájọ́ àti àyèọmọìlú. Facismo no ministério da justiça e cidadania.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário). Ìmúnisìn tipátipá, ìjọba ìmúnisìn tipátipá, s. totalitarismo (hitlerismo, fascismo, nazismo, nacional-socialismo). Nínú, prep. Dentro, no interior de. Ṣàkóso, s. Controlar. Ìṣe ìránṣẹ́, s. Ministério. Aṣàkóso, s. Ministro. Àyèọmọìlú, s. Cidadania. Ìdájọ́, s. Justiça.