terça-feira, 28 de novembro de 2017

Pecado

Ṣọ́ọ̀ṣì lágbàáyé ti Ìjọba Ọlọ́run.
Igreja Universal do Reino de Deus.Foto de Denise Chagas.


Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Táò,  ìsìn Táò, s. Tao, taoísmo.
Ìṣe Búdà, s. Budismo.
Ìṣe kọnfukiọsi, s. Confucionismo.  
Híńdù, Ìṣehíndù‎, ẹ̀sìn-ìn Híndù, s. Hinduísmo
Ìsìláàmù, ìmàle, s. Islamismo.
Ìṣekèfèrí titun, s. Neopaganismo, wicca. 
Jaini, s. Jainismo.
Ìsìn àwọn Júù, s. Judaísmo
Ìsìn Sikh, s. Siquismo.
Ṣintó, ẹ̀sìn ìbílẹ̀ Jèpánù, s. Xintoísmo.
Ṣọ́ọ̀ṣì ti pẹ́ńtíkọ́sì, ìjọ ti pẹ́ńtíkọ́sì, ilé Ọlọ́run ti pẹ́ńtíkọ́sì, s. Igreja pentecostal.
Ìjọ Ajíhìnrere, s. Igreja evangélica.
Ìjọ Kátólìkì, Ṣọ́ọ̀ṣì Kátólíìkì, s Igreja católica.
Ẹ̀sìn Kristi, ìsìn Kristi, ẹ̀sìn onígbàgbọ́, kirisẹ́ńdọ̀mù, s. Cristianismo. 
Ìṣeìjọánglíkánì, s. Anglicanismo.
Ìjọ ilẹ̀ Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì, s. Igreja anglicana.
Ìṣepurẹsibiteriani, s. Presbiterianismo.
Ṣọ́ọ̀ṣì Mẹ́tọ́díìsì, s Igreja metodista.
Ìjọ onígbàgbọ́, s. Congregação cristã.
Ṣọ́ọ̀ṣì Pùròtẹ́sítáǹtì, s. Igreja protestante. 
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́, s. Verdadeira Igreja de Jesus.
Ìṣeìjọkríslàm, ìṣekríslàm, ìṣekrísmàle, ìṣeìjọkrísmàle, ẹ̀sìn Krístì-ìmàle, s. Crislamismo. Sincretismo do cristianismo com o islã.
Ṣọ́ọ̀ṣì Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì ti Ìlà Oòrùn , s. Igreja ortodoxa oriental.
Baháí, s. Fé bahá'í
Ẹ̀sìn òrìṣà, s. Religião de orixá. 
Kandomblé, s. Candomblé.
Santería, s. Santeria.
Fúdù, s Vodum, vodun, voodoo ou vodu.
Ìgbàgbọ́ pé ẹ̀mí wà nínú ohun gbogbo, s. Animismo.
Ìjọsìn Sátánì, s. Satanismo.
Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà, s. Testemunhas de Jeová.
Ìjọ Jésù Krístì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹ́hìn, s. Igreja de Jesus Cristo dos Santos dos Últimos Dias.
Ẹ̀sìn àgbọn, s. Religião do coco.
Àìgbọlọ́rungbọ́, àìgbà-pọ́lọ́run-wà, s. Ateísmo. 
Agbátẹrù ìgbàgbọ́ Ọlọ́run-kò-ṣeé-mọ̀, s. Agnosticismo. 
Iṣẹ́ àjẹ́, iṣẹ́ oṣó, iṣẹ́ òkùnkùn, s. Feitiçaria.
Oògùn, idán pípa, iṣẹ́ àjẹ́, s. Magia.
Ẹ̀sìn ìbílẹ̀, iṣe gba àwọn ẹ̀mí àìrí gbọ́, s. Xamanismo.
Ìbẹmìílò, ìbẹmìílò ká, s. Espiritismo.
UMBANDA, s. Umbanda. Ó ju àádọ́rin mílíọ̀nù ọmọ ilẹ̀ Bràsíl tí wọ́n sọ pé ó ń lọ́wọ́ nínú ẹ̀sìn kandomblé, Umbanda, Ṣàngó, àtàwọn ẹ̀sìn míì táwọn Adúláwọ̀ mú wọ orílẹ̀-èdè náà - Diz-se que mais de 70 milhões de brasileiros, direta ou indiretamente, estão ligados ao candomblé, umbanda, xangô e outras religiões afro-brasileiras.

Ṣọ́ọ̀ṣì lágbàáyé, ṣọ́ọ̀ṣì pátápátás. Igreja Universal.
Ilẹ̀ọba, ìjọbas. Reino.
Gómìnà, s. Governo.
Ọba, s. Rei.
, pron. rel. Que, o qual, do qual, cujo.
, conj. Se. Enquanto, ao mesmo tempo que.
, prep. Desde que.
, v. Bater com a mão ou com algo na mão, acertar o alvo.
, adv. Onde, quando.
Ti, prep. de ( indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai).
Ti, ti...ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - ambos, eu e minha esposa.
Ti, v. Ter (verb. aux.). Arranhar. Pular.
Ti, v. interrog. Como. Ó ti jẹ́? - Como ele está.
Ti, adv. pré-v. Já. Indica uma ação realizada.
Ti, àti, conj. E.
Ti, part. pré-v. 1. Usada para indicar o tempo passado dos verbos. Èmi ti máa rìn lálé - Eu costumava caminhar à noite. 2. É usada com báwo ni - como - quando se deseja expressar sentimento e posicionada antes do verbo principal. Báwo ni àwọn ti rí? - Como eles estão?. 

Tìti, adv. Tremendamente, violentamente.
Títí, adv. Continuamente, constantemente.
Títí, prep. Até.
Tìtì, adv. Tremulamente, balançadamente.
Títì, adj. Trancado, que deve ser empurrado, fechado.
Títì, ọ̀nà, s. Via pública, rua, passagem.
Ti... ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - Ambos, eu e minha esposa.
Títi-àiyé, adv. Eternamente.
Títí dé, prep. Até. (referindo-se a um local ou espaço).
Títí di, prep. Até. (referindo-se a período de tempo).
Títí  láé, títí láí, adv. Perpetuamente, para sempre, definitivamente.
Títilọ, adv. Continuadamente, assim por diante.

Ọlọ́run, s. O dono do céu, o ser supremo.
Elédùmarè, Èlédùmàrè, s. Deus, a divindade suprema. 
Olódùmarè, Olódùmares. Deus, o onipotente.  
Èdùmàrè, s. Deus, o ser supremo do universo. Kí ni Ọlọ́run ń fẹ́? - Qual é a vontade de Deus? Ọlọ́run ùn mi Ọba Òkè, ògo ni fún orúkọ Elédùmarè Ọba Adániwáyé mágbàgbé ẹni. Ǹjẹ́ bàbá modúpẹ́ lọ́ọ̀rẹ, ọpẹ́ ìmọ̀, ọgbọ́n, òye tí Ẹ jogún fún mi, modúpẹ́. Modúpẹ́ àǹfààní tí O fún mi láti gbé yobamoodua kalẹ̀, mo sì dúpẹ́ pé ẹ̀mí wà, bí ẹ̀mí bá sì wà, ìrètí ń bẹ. Ọ̀báńjígì gba ọpẹ́ẹ̀ mi, modúpẹ́ -  Meu Deus, o Todo-Poderoso, a glória é o teu nome, Aquele que criou humano para viver na Terra. Pai, obrigado, obrigado para o conhecimento, sabedoria e compreensão que você tem dado para mim, eu agradeço. Obrigado pela oportunidade que me deu para criar yobamoodua, também sou grato pela vida, quando há vida, há esperança. Deus Todo-Poderoso aceitar o meu agradecimento.
Òrìṣà obìnrin, s. Deusa. A kì í fipá mú káwọn míì gba ohun tá a gbà gbọ́ lórí Òrìṣà obìnrin - Nós não devemos forçar ninguém a aceitar nossas crenças sobre Deusa.
Àwọn ọlọ́run àjúbàfún, s.  Deuses, deidades, divindades.
Ti Ọlọ́run, adj. Divino.

Ẹ̀ṣẹ̀, s. Pecado.

Nenhum comentário:

Postar um comentário