quinta-feira, 16 de fevereiro de 2017

Necessidades básicas

Àwọn àìní ìpilẹ̀ (necessidades básicas)




Pirâmide de Maslow




1. Ìmúṣẹ ti ara ẹni (realização pessoal):

Ìwà rere (moralidade), àtinúdá (criatividade), ìrọ̀rùn (espontaneidade), ojútùú ìṣòro (solução de problemas), àìní ti ìkórìíra (ausência de preconceito), ìtẹ́wọ́gbà ti àwọn òótọ́ (aceitação dos fatos).

2. Iyì (estima):

Ara-níyì (auto-estima), ìgbẹ́kẹ̀lé (confiança), àṣeyọrí (conquista), ọ̀wọ̀ ti ẹlòmíràn (respeito dos outros), ìbọ̀wọ̀ fún ẹlòmíràn (respeito aos outros).

3. Ìfẹ́ (amor), ìbáṣepọ̀ (relacionamento):

Ọ̀rẹ́, ìbárẹ́, ìbáṣọ̀rẹ́ (amigo, amizade), ẹbí (família), ìfamọ́ra ìbálòpọ̀, ìfamọ́ tímọ́tímọ́ ìbálòpọ̀ (intimidade sexual).

4. Ààbò (segurança): 

Ààbò ti ara (segurança do corpo), ààbò iṣẹ́ (segurança do emprego), ààbò àwọn àlùmọ́nì (segurança de recursos), ààbò ìwà rere (segurança da moralidade), ààbò ẹbí (seguraça da família), ààbò ìlera (segurança da saúde), ààbò ìní (segurança da propriedade).

5. Ẹ̀kọ́ ìmú ṣiṣẹ ẹlẹ́ẹ̀mín (fisiologia): 

Èémí (respiração), ońjẹ, ounjẹ (comida), omi (água), ìbálòpọ̀ (sexo), oorun (sono), homeostasis (homeostase), yomijáde, ìyàsápákan omi ara (secreção, excreção).


Aeroporto Espacial

Pápá ọkọ̀-àlọbọ̀ òfurufú, pápá ọkọ̀-ayára òfurufú (espaçoporto)





Elevador espacial

Ẹ̀rọ ìgbé nkan sókè òfurufú.
Elevador espacial.





Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Ẹ̀rọ ìgbé nkan sókè, ohun èlo ìgbé nkan sókè, s.  Elevador, ascensor.
Òfurufú, òfuurufú, s. Espaço sideral, espaço profundo,  ar, firmamento, céu.

Vôos realizados

Àwọn ìfòlókè tótiparí (vôos realizados)

Estação Espacial Internacional


Ibùdó Òfurufú Akáríayé (Estação Espacial Internacional)


Sonda espacial

Ọkọ̀-òfurufú (sonda espacial). 

É uma nave espacial não tripulada, utilizada para a exploração remota de outros planetas, satélites, asteroides ou cometas.





Centro espacial

Gbọ̀ngàn Òfurufú (centro espacial)

Ônibus espacial

Ọkọ̀-ayára Òfurufú, Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú (ônibus espacial, vaivém espacial)


Àwọn ìránlọṣe àwọn Ọkọ̀-ayára Òfurufú - Missões dos ônibus espaciais.



Ônibus espacial Discovery


Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Ìránlọṣe, s. Missão.
Àwọn, wọn, pron. Eles elas. Indicador de plural. 
Òfurufú, òfuurufú, s. Espaço sideral, ar, firmamento, céu.
Ọkọ̀, s. Canoa, veículo, carro.

Ladrão

Olè, jàgùdà, ọlọ́ṣà (ladrão)