domingo, 16 de julho de 2017

Utensílios de cozinha

Àwọn ohun èlò ìdáná (utensílios de cozinha)



 Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).
                                                                           Utensílios para Forno e Fogão

Gírìdì, s. Grade, grelha, assadeira.
Àpótí ìyọ, bátànì agbada, ohun èlò bàbà , s. Fôrma, molde.
Àwopẹ́tẹ́, s. Fôrma redonda para bolo
Aṣọ tá a fi ń nu àwo nu ọwọ́ mi, s. Pano de prato.
Ohun èlò tí a fi ń ṣí agolo, s. Abridor de latas, abre-latas.
Ọ̀bẹ, s. Faca.
Àlùmágàjí, s. Tesoura, alicate.

Utensílios para Preparo de Alimentos

Ìkòkò, s. Pote, vasilha.
Ohun èlò tó ń lo iná mànàmáná, s. Panela elétrica.
Ife, s. Copo.
Abọ́, àwo, àwo pẹrẹsẹ, s. Prato.
Ìkòkò ìseńjẹ, s. Panela. 
Ìṣà omi, s. Jarros.
Òṣùwọ̀n, s. Balança.
Àwo láti lù àkàrà, s. Tigela para bater bolo.
Ṣíbí, s. Colher de metal.  
Ìgbákọ, ìgbakọ, s. Colher grande de madeira, concha.
Àmúga, s. Garfo.
Òòlù, s. Martelo.
Àwopẹ́tẹ́, s. Assadeira, frigideira, forma redonda para bolo.
Àwojẹ, s. Prato de estanho.
Àwokótó, àwoo kótó, s. Bacia, prato raso.
Àwo-ọlọ́gbún, s. Prato oval.
Àwo-ọlọ́mọrí, s. Bacia com tampa.
Bàsíà, s. Bacia.
Àwopọ́kọ́, s. Travessa, prato grande.
Àwo-iyọ̀, ìgò iyọ̀, s. Saleiro.
Àwo, s. Pires.
Odó, s. Pilão para amassar inhame.
Ọmọ odó, ọmọrí-odó, s. Bastão para amassar o alimento no pilão, braço do pilão
Kọ̀nkọ̀sọ̀, s Peneira feita de palha, coador. 
Asẹ́, s Coador, peneira, filtro.  
Ajere, aje, s Coador, peneira, pote perfurado para cozinhar alimenton no vapor ou escorrer sedimentos.
Pákó, pátákó, àga tábìlì, s Tábua.
Ohun èlò láti ṣe kọfí, s. Cafeteira.  

Utensílios para Servir Alimentos

Abọ́ pẹrẹsẹ, s. Bandeja.
Ìgbákọ, ìgbakọ, s. Colher grande de madeira, concha.
Abẹ̀rọ, s Colher, espátula de madeira. 
Ṣọ́bìrì, s Pá, escavadeira, cavadeira, espátula. Ferramenta formada de uma chapa de ferro ou de madeira mais ou menos côncava, ajustada a um cabo e destinada a remover terra. 
Ṣíbí láti gbà áásìkiriìmù, s. Colher para sorvete.
Àwopọ́kọ́ fún kéèkì, s. Prato para bolo. 
Àmúga láti gbà Oúnjẹ alápòpọ̀, s. Pegador de macarrão.


Utensílios para Bebidas

Ohun èlò kọfí, s. Cafeteira.
Ohun èlò omi, s. Chaleira.
Asẹ́, s. Coador.
Ẹ̀rọ láti fà omi èsokéso, s. Espremedor.
Ìrọmi, ìrọtí, àrọ, s. Funil.
Ìgò ṣìṣù, s. Garrafas plásticas.
Ohun èlò amú-nǹkan-gbóná, s. Garrafa térmica. 
Ìṣà omi, s. Jarros.
Ohun èlò ti wàrà, s.  Leiteira
Ohun èlò láti pò àwọn ohun-mímu, s. Misturador de bebidas.
Abọ́ àdému kékeré, s. Vasilha pequena.
Kòlòba, s. Vasilha para guardar ingredientes e provisões.
Ìkòkò, s. Pote, vasilha.


Utensílios para Colocar à Mesa


Ìgò láti fi àwọn nǹkan amóúnjẹ-ta-sánsán, s. Porta temperos.
Ìbora oúnjẹ, s. Cobridor de alimento.
Ohun láti fi igi eyín, s. Paliteiro.
Ìgò láti fi ata, s. Pimenteiro
Ọlọ ata, s. Moedor de pimenta.
Àtìlẹ́yìn fún agolo epo àti òróró, s. Porta lata de azeite e óleo.
Ìkòkò fún wàràkàṣì gé sí wẹ́wẹ́ kún un, s. Pote para queijo ralado.
Àtìlẹ́yìn láti fi àwọn ohun èlò tí wọ́n fi ń se oúnjẹ, s Porta talheres.
Ohun èlò láti fọ́ oríṣiríṣi ẹ̀pà, s. Quebra-nozes.
Àwo-ọlọ́mọrí láti fi wàràkàṣì, s. Queijeira.
Ohun-èlò láti fà ìdérí, s. Saca-rolhas.
Kọ́ọ̀bù, s. Xícara.
Ohun èlò láti fi sàláàdì, s. Saladeira.
Àwopọ́kọ́, s. Travessa, prato grande.
Ṣíbí, s. Colher de metal.  
Ìgbákọ, ìgbakọ, s. Colher grande de madeira, concha.
Àmúga, s. Garfo.
Abọ́, àwo, àwo pẹrẹsẹ, s. Prato.
Aṣọ orí tábìlì, s. Toalha de mesa.
Kọ́ọ̀bù, ife, ago, s. Copo. 
Àwo-iyọ̀, ìgò iyọ̀, s. Saleiro.
Àwo, s. Pires.
Àwo ẹlẹgẹ́, àwokòtò, sTigela
Àwokòtò wúrà, s. Tigela de ouro.
Àwo ọbẹ̀, s. Tigela de cozido.
Àwọn ohun èlò tí wọ́n fi ń se oúnjẹ, s. Talheres (garfo, colher e faca)
Ohun èlò tíì, ìkòkò tíìs. Bule de chá.
Àwo ṣúgà, s.  Açucareiro. 
Ohun èlò láti fi bọ́tà, s. Manteigueira.
Apẹ̀rẹ̀ láti fi búrẹ́dì, s. Cesto de pão.
Ìkòkò láti fi omi èso fí a fi iyọ̀ òyìnbó dì, s. Pote para geleia.
Ìkòkò láti fi oyin, s. Pote para mel.
Ohun èlò láti fi aṣọ ìnujúgèlè, s. Porta-guardanapos.
Ohun èlò láti fi ọbẹ̀, àwokòtò láti fi ọbẹ̀, s. Molheira.
Apẹ̀rẹ̀ áti fi èso, ohun èlò láti fi èsos. Fruteira.
Garawa láti fi omidídì, s. Balde para colocar gelo.
Ohun èlò láti gbámú omidídì, s. Pegador de gelo.

Outros Utensílios Básicos para a Cozinha


Ohun èlò láti múgbẹ àwo pẹrẹsẹ, s. Escorredor de pratos.
Aago ibi ìdáná, s. Relógio de cozinha.
Ìgbálẹ̀, s. Vassoura.
Ìnulẹ̀, s. Rodo. 
Ìnulẹ̀ kékeré, s. Rodinho.
Ohun èlò láti gbébọ́ èérí ní àwo-ìfọwọ́, s. Desentupidor para pia.
Àwo-ìfọwọ́, s. Pia.
Ohun ìkódọ̀tísí, s. Lixeira. 
Ìkòkò láti fi oúnjẹ. Potes de mantimentos
Àpò onírọ́bà láti fi nínú ti ẹ̀rọ amú-ǹkan-tutù, s. Plásticos para freezer.
Ẹ̀rọ amú-ǹkan-tutù, s. Freezer.
Ẹ̀rọ tí ń mú ǹkan tutù, s. Geladeira.
Sítóòfù, s. Fogão.
Àdògán dáná, s.  Fogão a lenha.
Àdìrò, ààrò, àrò, ẹ̀rọ ìdáná, s. Lareira, forno. 
Àdìrò ìgbì kékeré, s. Forno de micro-ondas.
Ẹ̀rọ tó ń fọ abọ́, s. Máquinas de lavar louça.
Àpótí ìkó-ǹkan ilé ìdáná, s. Armário de cozinha.
Tábìlì, s. Mesa.
Àga, s. Cadeira.
Ohun èlò láti hó ewébẹ̀, s. Descascador de legumes.
Asẹ́, s Coador, peneira, filtro. 
Ọlọ ọ̀bẹ, s. Amolador de faca.







Ferramentas

Àwọn irinṣẹ́ (ferramentas)




Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Irin tí wọ́n fi ń fà jáde ìṣó, s. Pé-de-cabra.
Irin kan tí wọ́n fi ń ṣí ilẹ̀kùn, s. Alavanca.
Irin kọdọrọ, s. Esquadro.
Okùn ìwọ̀n, s. Prumo.
Ẹfun láti fi fa ìlà, s. Giz de linha.
Àáké tí wọ́n fi ń bó èèpo igi, s. Machado. 
Àáké, s. Enxó O enxó (do latim asciola) é um instrumento composto por um cabo curto e uma chapa de aço cortante. É usado por carpinteiros e tanoeiros para desbastar a madeira.
Ayùn, s. Serrote, serra.
Òòlù onírins. Martelo
Òòlù, s. Martelo.
Òòlù onígi, s. Malho. Grande martelo, de cabeça pesada, sem unhas nem orelhas, próprio para bater o ferro e que, para mais fácil manejo, se pega com ambas as mãos.
Ohun tí wọ́n fi ń gbẹ́ nǹkan, s. Formões.
Irin tí wọ́n fi ń lu ihò sára igi, irin tí yóò máa fi okùn ọrun yí bírí láti fi lu ihò sára igi, s.  Arco de pua artesanal.
Àtè, s. cola.
Ìṣó, s. Prego.
Ìgbálẹ̀ kékeré,  ṣọ́bìrì kékeré, s. Chave de fenda.
Kọ́kọ́rọ́, s. Chave.
Dòjé, s. Foice.
Ọkọ́, s. Enxada, estribo.
Ìfági, s. Plana.
Ìfá, s. Ferramenta com dois cabos usada para escavar a polpa de cabaça verde.
Ìdè, s. Ato de amarrar, escravidão. Parafuso, fivela, cinta.
Èlò táa fi ń dáhò sí nǹkan, s. Furadeira.
Mítà, s. Metro.
Ọ̀pá ìdíwọ̀n díwọ̀n igun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ilẹ̀ ayé, s. Régua, medida, bitola.
Ọ̀pá òṣùnwọ̀n, s. Vara que serve para medir.
Rúlà olóròó, s. Régua vertical.
Ìfàlà, s. Régua.