terça-feira, 8 de maio de 2018

Espírito Núbio

Ẹ̀mí ará nubia: ẹ̀sìn ìbílẹ̀  àti  ìtàn àròsọ lásán tẹ̀mí.                                                 
Espírito núbio:  religião antiga e mitologia espiritual.

Imagem

Lupita Nyong'o como rainha núbiaÀkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Ẹ̀mí, s. Espírito.
Ará, s. Parente, habitante de um lugar, um conhecido, irmandade. Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà - República Popular da China.
Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão.
História , s. Historia antiga.
Ìtàn, s. Mitos, histórias. 
Àtijọ́, s. Tempo antigo.
Ílẹ̀ọba Kúṣì, s. O Reino de Kush.  (Sáàmù 104:18) Àwọn ewúrẹ́ òkè ńlá bíi àwọn ewúrẹ́ orí òkè Nubia tí ìwo wọn lẹ́wà gan-an, wà lára àwọn ẹ̀dá tí ẹsẹ̀ wọn le gírígírí ju gbogbo ẹ̀dá tó ń gbé orí àwọn òkè ńlá lọ - (Salmo 104:8) Os cabritos monteses — como o íbex-núbio, de chifres magníficos — estão entre os que escalam os montes com mais equilíbrio e segurança.
Ẹ́gíptì, s. Egito. 
Ìjba, s. Governo, reino.
Fáráò Ẹ́gíptì, s. Faraó do Egito.
Netjerikhet, Djoser, s.  Neterket, Djozer, Zhoser ou Geser.
Ilẹ̀ Nubia, s. Núbia.
Àròsọ inú ìmọ̀ ìjìnlẹ̀, s. Ficção científica.
Ìtàn àtẹnudẹ́nu, s. Lenda.
Àròsọ lásán, ìtàn àròsọ, èrò èké, ìtàn àròsọ lásán, s. Mito.
Àwọn ẹ̀sìn ayé àtijọ́, s. Religiões antigas.
Agbára ìsúnniṣe, s. Inspiração.
Ìtọ́sọ́nà, s. Orientação. 
Ìtàn àròsọ kan táwọn Gíríìkì àtàwọn ará Róòmù, s. Mitologia grega e e romana. 
Ìtàn àròsọ àwọn Gíríìkì, Mitologia grega.
Ìtàn ìwáṣẹ̀ ilẹ̀ Íjíbítì, s. Mitologia egípcia. Nínú ìtàn ìwáṣẹ̀ ilẹ̀ Íjíbítì, Bes yìí ni ọlọ́run àríyá, oníwà pálapàla sì ni” -  Na mitologia egípcia, Bes é o deus lascivo das festanças”.
Àwọn Néfílímù, s. Nefilins. Àwọn Néfílímù Nínú Ìtàn Ìwáṣẹ̀ Kẹ̀? - Os nefilins na mitologia?
Ìtàn ìwáṣẹ̀ àwọn ará Bábílónì, s. Mitologia  babilônica.
Oúnjẹ tẹ̀mí, s. Comida espiritual. 
Àwọn ohun tẹ̀mí wa ṣíṣeyebíye, s. Valores espirituais.
, conj. pré-v. E, além disso, também. Liga sentenças, porém, não liga substantivos; nesse caso, usar " àti". É posicionado depois do sujeito e antes do verbo.
Àti, Conj. E. Usada entre dois nomes, mas não liga verbos.

Ẹ̀sìn, ìsìn, s. Religião. 
Ẹ̀sìn ìbílẹ̀, s. Religião tradicional, religião originária.
Táò,  ìsìn Táò, s. Tao, taoísmo.
Ìṣe Búdà, s. Budismo.
Ìṣe kọnfukiọsi, s. Confucionismo.  
Híńdù, Ìṣehíndù‎, ẹ̀sìn-ìn Híndù, s. Hinduísmo
Ìsìláàmù, ìmàle, s. Islamismo.
Ìṣekèfèrí titun, s. Neopaganismo, wicca. 
Jaini, s. Jainismo.
Ìsìn àwọn Júù, s. Judaísmo
Ìsìn Sikh, s. Siquismo.
Ṣintó, ẹ̀sìn ìbílẹ̀ Jèpánù, s. Xintoísmo.
Ṣọ́ọ̀ṣì ti pẹ́ńtíkọ́sì, ìjọ ti pẹ́ńtíkọ́sì, ilé Ọlọ́run ti pẹ́ńtíkọ́sì, s. Igreja pentecostal.
Ìjọ Ajíhìnrere, s. Igreja evangélica.
Ìjọ Kátólìkì, Ṣọ́ọ̀ṣì Kátólíìkì, s Igreja católica.
Ẹ̀sìn Kristi, ìsìn Kristi, ẹ̀sìn onígbàgbọ́, kirisẹ́ńdọ̀mù, s. Cristianismo. 
Ìṣeìjọánglíkánì, s. Anglicanismo.
Ìjọ ilẹ̀ Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì, s. Igreja anglicana.
Ìṣepurẹsibiteriani, s. Presbiterianismo.
Ṣọ́ọ̀ṣì Mẹ́tọ́díìsì, s Igreja metodista.
Ìjọ onígbàgbọ́, s. Congregação cristã.
Ṣọ́ọ̀ṣì Pùròtẹ́sítáǹtì, s. Igreja protestante. 
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́, s. Verdadeira Igreja de Jesus.
Ìṣeìjọkríslàm, ìṣekríslàm, ìṣekrísmàle, ìṣeìjọkrísmàle, ẹ̀sìn Krístì-ìmàle, s. Crislamismo. Sincretismo do cristianismo com o islã.
Ṣọ́ọ̀ṣì Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì ti Ìlà Oòrùn , s. Igreja ortodoxa oriental.
Baháí, s. Fé bahá'í
Ẹ̀sìn òrìṣà, s. Religião de orixá. 
Kandomblé, s. Candomblé.
Santería, s. Santeria.
Fúdù, s Vodum, vodun, voodoo ou vodu.
Ìgbàgbọ́ pé ẹ̀mí wà nínú ohun gbogbo, s. Animismo.
Ìjọsìn Sátánì, s. Satanismo.
Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà, s. Testemunhas de Jeová.
Ìjọ Jésù Krístì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹ́hìn, s. Igreja de Jesus Cristo dos Santos dos Últimos Dias.
Ẹ̀sìn àgbọn, s. Religião do coco.
Àìgbọlọ́rungbọ́, àìgbà-pọ́lọ́run-wà, s. Ateísmo. 
Agbátẹrù ìgbàgbọ́ Ọlọ́run-kò-ṣeé-mọ̀, s. Agnosticismo. 
Iṣẹ́ àjẹ́, ié um feiticeiro, quebrou a escuridão , s. Sentimentos
Drogas, feitiçaria , feitiçaria , s. Magia.
Religião religiosa, eu acredito em demônios , s. Xamanismo.
Espiritismo, espiritismo , s. Espiritismo.
UMBANDA , s. Umbanda Mais de setenta milhões do Brasil, que disse que ele estava envolvido na religião kandomblé, Umbanda, Xangô, país Afro religiosa e outra - Diz-que Mais de 70 Milhões brasileiros, Direta ou indiretamente, estao ligado ao candomblé, umbanda, xangô e outras religiões afro-brasileiras.


Nenhum comentário:

Postar um comentário