sexta-feira, 19 de outubro de 2018

Nazismo no Brasil

Ọ̀pọ̀ àwọn ará Bràsíl fẹ́ Ìjọba Násì kan 
Muitos brasileiros querem um governo nazista.



A imagem pode conter: comida



Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).



Ọ̀pọ̀, s. Plenitude, grande quantidade, multidão.
Ọ̀pọ̀lọ́pọ̀, adj. Numeroso, abundante.

Onírúurú, adj. Vários, diferentes.
Púpọ̀, adj. Muito.
Púpọ̀-púpọ̀, adv. Abundantemente.

Àwọn, wọ́n, pron. pess. Eles, elas. Indicador de plural.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Àwọn ará Bràsíl, s. Brasileiros.

Ọmọ orílẹ̀-èdè Bràsíl, ọmọ ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileiro, brasileira.

Ti orílẹ̀ èdè Bràsíl, adj. Do Brasil; 

Tó jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Bìràsílì, tó jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Bràsíl, tí a bí ní ilẹ̀ Bràsíl, adj. Brasileiro, brasileira.

Obìnrin ọmọ Bràsíl, obìnrin ọmọ ilẹ̀ Bràsíl, obìnrin ará Bràsíl, obìnrin tó jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileira.

Ọkùnrin ọmọ Bràsíl, ọkùnrin ilẹ̀ Bràsíl, 

ọkùnrin ará Bràsíl, ọkùnrin tó jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Bràsíls. Homem Brasileiro.

Ẹlẹ́yàpúpọ̀, s. Indivíduo mestiço, colorido ou multirracial.
Adúláwọ̀, s. Negro.

Ènìyàn dúdú, s. Negro.
Dúdú, v. Ser preto.
Dúdú, adj. Negro.

Ará, s. Parente, habitante de um lugar, um conhecido, irmandade. Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà - República Popular da China.
Ará, s. Parente, habitante de um lugar, um conhecido, irmandade. Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà - República Popular da China.
Èèpo, s. Palha, casca, pele, vagem, concha.
Awọ ara, s. Pele.
Awọ, s. Pele humana ou de animal, pelo.

Ẹnì, s. Pessoa.
Ẹní, s. Esteira, capacho.

Fẹ́, v. Querer, desejar.  
Ìtàn lásan, s. História em vão, mito. 
Àròsọ, s. Rumor, boato, hipótese, mito. 
Àlọ́, s. Mito ( enigma, adivinhação). 
Ìtàn àròsọ ayé, s. Mito. 
Ìtàn, s. Mitos, histórias, episódio. 
Èrò tí kò tọ́, s. Idéia equivocada, ideia errada, mito.
Tó wà nínú wa, adj. Que está em nós.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kúbà, s. República de Cuba.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Aparapọ̀ ilẹ̀ Bràsíl, s. República Federativa do Brasil. Ìwé ìròyìn kan tí wọ́n ń tẹ̀ lórílẹ̀-èdè Bràsíl sọ pé irú ìwàásù bí èyí làwọn ìsìn kan lórílẹ̀-èdè Bràsíl sábà máa ń ṣe - Essa é a mensagem difundida por certos grupos religiosos no Brasil, segundo um jornal desse país.
Orílẹ̀-èdè Bràsil, ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasil, Pindorama.
Ìpínlẹ̀ Ogunlọ́gọ̀ Orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Bòlífíà, s. Estado Plurinacional da Bolívia
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Bòlífárì ilẹ̀ Fẹnẹsúélà, s. República Bolivariana da Venezuela.
Orílẹ̀-èdè Fẹnẹsúélà, ilẹ̀ Fẹnẹsúélà, s. Venezuela.
Ìmúnisìn tipátipá, ìjọba ìmúnisìn tipátipá, s. Totalitarismo (hitlerismo, fascismo, nazismo, nacional-socialismo).
Ìjọba Aláṣẹ Oníkùmọ̀, s. Facismo.

Ti ìpilẹ̀ṣẹ̀, ti ìpilẹ̀ṣẹ̀pàtàkì, adj. Substancial, medular, crucial, relevante, primeiro, primordial, mestre, principal, necessário, importante, básico, capital, essencial, imprescindível, indispensável, vital, elementar.
Ìṣekápítálístì, ìṣeòwòèlé, kapitálísíìmù, s. Capitalismo.
Aṣekápítálístì, s. Capitalista.
Ìsọ-lẹ́tà-di-ńlá, s. Capitalização.
Kó ọrọ̀ jọ,  kó owó jọ, s. Capitalizar.
Ìṣesósíálístì, s. Socialismo.
Ìṣekọ́múnístì, s. Comunismo.
Ìjọba Násì, s. Nazismo.
Ìjọba Kọ́múníìsì, s. Governo comunista.
Ìsọ̀kan àwọn Orílẹ̀-èdè Olómìnira Sófíẹ́tì Sósíálístì, s. União das Repúblicas Socialistas Soviéticas
Ìsọ̀kan Sófìẹ̀tì, s. União Soviética.
Lòdì sí òṣèlúaráìlú, adj. Antidemocrático.

Ìjọba àjùmọ̀ṣe, s. Democracia.
Ìjọba ológun, s. Ditadura militar, governo militar.
Ìjídìde proletárì, s. Revolução proletária.

Ẹgbẹ́ kọ́múnístì, s. Partido comunista.
Aṣekọ́múnístì, s. Comunista.
Ìṣeàìlólórí, s. Anarquismo.
Ìṣesósíálístì ti ọ̀rọ̀ lásán àròsọ, s. Socialismo utópico.
Ìṣesósíálístì ti sáyẹ́nsì, s. Socialismo científico.
Ìṣeohunayé ti ìtàn, s. Materialismo histórico.
Ìjídìde proletárì, s. Revolução proletária.

Àwọn kan, pron. Alguns. Ó lè ṣòro fún àwọn kan láti gba ìbáwí - Para alguns, isso pode ser um verdadeiro desafio.
Àwọn kan lára àwọn, pron. Alguns dos.  
Àwọn lẹ́rìí kan, s.  Algumas testemunhas.   Àmọ́ o, àwọn kan ò lè lo gbogbo àkókò wọn lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn báyìí torí ipò tó yí wọn ká -  É claro que alguns não podem servir no tempo integral no momento por causa de suas circunstâncias. 
Àwọn Kristẹni kan, s. Alguns cristãos. Àwọn kan ti nígbàgbọ́ rí, àmọ́ wọn ò dúró sínú ìfẹ́ Ọlọ́run - Alguns que tinham fé não permaneceram no amor de Deus. Àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì kan ronú pé, níwọ̀n bó ti jẹ́ pé kò tíì pẹ́ tí ọ̀rọ̀ yíyí àbùdá irè oko padà bẹ̀rẹ̀, ó yẹ kí àyẹ̀wò ṣì máa lọ lórí rẹ̀ nípa àwọn ewu tó lè ṣe fún àwọn tó ń jẹ ẹ́ - Alguns cientistas acham que é muito cedo para avaliar os alimentos GM e que seriam necessários mais testes para detectar possíveis riscos para os consumidores.
Àwọn akéde kan, s. Alguns publicadores. 

Kàn án mọ́gi!, v. imper. Crucifica-o!, Para a estaca com ele!  Bẹ̀rẹ̀ sí fẹ̀sùn kàn án - Começou a acusá-lo.
Ìkan, ọ̀kan, num.  Um.
Kan, v. Tornar azedo.
Kan, adj. Amargo, ácido, azedo. Longe, ao largo.
Kan, num. e art. Um, uma. 

Kàn, adv. pré. v. Somente, simplesmente.
Kàn, v. Atingir, tocar, alcançar. Pregar com um martelo. Bater na porta, bater com a cabeça como um carneiro. Girar, retornar, fazer um rodízio. Referir-se a, aludir, recorrer. Devolver, interessar alguém.
Kán, v. Pingar, gotejar ( a chuva ou qualquer líquido). Quebrar, partir, estalar algo sólido.
Mọ́gi, s. Estaca. 

Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão.
Ilẹ̀ Bràsíl, Bràsíl, s. Brasil, Pindorama.
Orílẹ̀-èdè, s. Nação, país.
Orílẹ̀, s. Grupo de origem ou clã.
Èdè, s. Língua, idioma, dialeto, linguagem.
Olómìnira, adj. Independente.
Àpapọ̀, s. Soma, total, combinação, ato de unir, de juntar
Aparapọ̀, adj. Federativa.

Ààrẹ, s. Presidente.
Ìjọba, s. Governo, reino.
Gómìnà, s. Governo. 
Àkóso, àkóso ìlú, s. Restrição, controle, governo, administração. Àkóso lọ́wọ́: Regulado por. Àkójọ àwọn gómìnà ìpínlẹ̀ Nàìjíríà - Lista de governadores dos estados da Nigéria. 
Ìtọ́nà, s. Governo, tutela. 
Ìfọ̀nàhàn, s. Direção, guia.
Ìjọba-araẹni, s. Governo autônimo.
Ìjọba kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà, s. Apartheid, governo do apartheid. Lẹ́yìn tó fi ilé ìwé sílẹ̀, ó ṣiṣẹ́ sójà ìjọba kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà tẹ́lẹ̀ rí ti Gúúsù Áfíríkà - Depois de deixar a escola, serviu no exército da África do Sul no anterior governo do apartheid. Lákòókò tá à ń sọ yìí, Gúúsù Ìwọ̀ Oòrùn Áfíríkà wà lábẹ́ àkóso ìjọba kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà ti Gúúsù Áfíríkà - Naquela época, a África do Sudoeste estava sob o regime do apartheid (segregação racial), da África do Sul.
Ráíkì, s. Reich, reinado, região, rico, um império, reino, nação. Ìtúká Ráíkì Kẹta - Dissolução do Terceiro Reich.
Ti mú, adj. Preso, detido. “Wọ́n ti mú mi, wọn ò sì gbọ́ ẹjọ́ mi tí wọ́n fi dájọ́ ikú fún mi -  “Fui detido e sentenciado à morte — sem ter tido um julgamento.
Sí ọgbà ẹ̀wọ̀n, prep.+ s. Para a prisão.
Lọ́gbà ẹ̀wọ̀n, prep. + s. Na prisão. 
Láwọn àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́, prep. + s.  Nos campos de concentração.
Tó wà ní àwọn àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́, adj. Que estão nos campos de concentração.
Àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́, s. Campo de concentração. 
Ọmọ ogun adàlúrú, s. Guerrilheiro.

Àwọn gbólóhùn (frases)


Ẹni tí ó jẹ́ ìtàn àròsọ -Aquele que é mito.
Ẹni tí ó jẹ́ ìtàn lásanAquele que é mito.
Ilẹ̀  Bràsíl ló jẹ wá lógún jù lọ - Brasil acima de tudo.
Ilẹ̀ Bràsíl ju ohunkóhun mìíràn - Brasil acima de tudo.
Ọlọ́run ló jẹ wá lógún jù lọ - Deus acima de tudo.
gbẹ́ òṣèlú mi ni Orílẹ̀-èdè Bràsíl - Meu partido é o Brasil.
Jọ̀wọ́, lọ sí Orílẹ̀-èdè Kúbà - Jọ̀wọ́, lọ sí Orílẹ̀-èdè Kúbà - Por favor, vá para Cuba.
Mú ìṣekọ́múnístì kúrò lórí wa -  Afasta o comunsmo de nós, fora comunismo. 
Ilẹ̀ Bràsíl kì yóò run bi Orílẹ̀-èdè Fẹnẹsúélà - Brasil não será destruído como a nação da Venezuela.
Ilẹ̀ Bràsíl kì yóò di Fẹnẹsúélà kan - O Brasil não vai se tornar uma Venezuela.



Antipetismo


Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwà kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà wà ní aṣòdì sí ìṣe Ẹgbẹ́ ti àwọn Òṣìṣẹ́.
Há muito de racismo no antipetismo.

Resultado de imagem para racismo antipetismo


Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Ọ̀pọ̀lọpọ̀, adj. Numeroso, abundante.

Onírúurú, adj. Vários, diferentes.
Púpọ̀, adj. Muito.
Púpọ̀-púpọ̀, adv. Abundantemente.
Ìwà, s. Comportamento, conduta. 
Ìṣẹlẹ́yàmẹ̀yà, ẹlẹyamẹya, ẹ̀mí kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà,  ìwà kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà, s. Racismo. Ní Erénà 21, ọdún 2012, Ọ̀gbẹ́ni Ban Ki-moon tó jẹ́ ọ̀gá àgbà Àjọ Ìparapọ̀ Àwọn Orílẹ̀-Èdè sọ pé: “Ọ̀pọ̀ àdéhùn àti àwọn nǹkan ajẹ́bíidán míì tó gbéṣẹ́ wà kárí ayé tí a lè lò láti fi mú kí ìwà kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà, àìfẹ́ rí àjèjì sójú àti àìrára gba nǹkan sí kásẹ̀ nílẹ̀ tàbí kó má tiẹ̀ rú yọ rárá - O secretário-geral da ONU, Ban Ki-moon, disse em 21 de março de 2012: “Há muitos tratados e dispositivos, bem como um programa global, para impedir e erradicar o racismo, a discriminação racial, a xenofobia e a intolerância.

Tó wà láàárín àwọn ẹ̀yà, kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà, adj. Racial. 
Aláìfẹ́irúẹ̀dáọmọẹnìkéjì, s. Racista.
Ìkóríra, ìkórìíra, s. Ódio.
Ìṣojúsàájú, s. Parcialidade, favoritismo, xenofobia.

Àìfẹ́ rí àjèjì sójú, s. Xenofobia.
Ìkórìíra tó wà láàárín àwọn ẹ̀yà, s. Ódio racial. 
Ìṣòro kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà, s. Tensão racial.
Híhùwà ipá, s. Violência.
Ìwà ipá, s. Violência. Kí ló ń fa ìwà ipá yìí? - O que causa essa violência?
Híhùwà ipá sí àwọn obìnrin, s. Violência contra as mulheres.

, v. Vir. Procurar por, buscar, vasculhar. Tremer de nervoso. Dividir, partir em pequenos pedaços.
, v. Ser, haver, existir, estar.
, V. Cavar. Remar, dirigir. Abraçar, prender, apertar . Monopolizar.
Wà, àwa, pron. pess. Você.
Wa, pron. oblíquo. Nos, conosco. Possui função reflexiva e é posicionado depois de verbo e preposição.
Wa, pron. poss. Nosso, nossa.
Àwọn, wọ́n, pron. pess. Eles, elas. Indicador de plural.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Òṣìṣẹ́ tó ń gbowó iṣẹ́, s. Assalariado.
Òṣìṣẹ́, oníṣẹ́, s. Trabalhador, operário, proletário.

Aṣòdì sí Kristi, s. Anticristo.
Àntí, pref. Anti, contra, em oposição a. 
Mọ́, prep. Contra.
Ọ̀kánkán, prep. Contra, em oposição, em frente a. 
, prep. Contra, para, com, em, junto de.
Àntí, pref. Contra.
Aṣòdì, òṣòdì, s. Adversário, oponente.
Lòdì, adj. Contrário, adverso.
Lòdì sí, prep. Contra.
, prep. Para, em direção a. Indica movimento direcional.

, conj. pré-v. E, além disso, também. Liga sentenças, porém, não liga substantivos; nesse caso, usar " àti". É posicionado depois do sujeito e antes do verbo.

Ẹgbẹ́, s. Sociedade, associação, clube, partido. Companheiro, par. Posição, classe.
Ti lọ, adj. Desaparecido.
, pron. rel. Que, o qual, do qual, cujo.
, conj. Se. Enquanto, ao mesmo tempo que.
, prep. Desde que.
, v. Bater com a mão ou com algo na mão, acertar o alvo.
, adv. Onde, quando.
Ti, prep. de ( indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai).
Ti, ti...ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - ambos, eu e minha esposa.
Ti, v. Ter (verb. aux.). Arranhar. Pular.
Ti, v. interrog. Como. Ó ti jẹ́? - Como ele está.
Ti, adv. pré-v. Já. Indica uma ação realizada.
Ti, àti, conj. E.
Ti, part. pré-v. 1. Usada para indicar o tempo passado dos verbos. Èmi ti máa rìn lálé - Eu costumava caminhar à noite. 2. É usada com báwo ni - como - quando se deseja expressar sentimento e posicionada antes do verbo principal. Báwo ni àwọn ti rí? - Como eles estão?.
Tìti, adv. Tremendamente, violentamente.
Títí, adv. Continuamente, constantemente.
Títí, prep. Até.
Tìtì, adv. Tremulamente, balançadamente.
Títì, adj. Trancado, que deve ser empurrado, fechado.
Títì, ọ̀nà, s. Via pública, rua, passagem.
Ti... ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - Ambos, eu e minha esposa.
Títi-àiyé, adv. Eternamente.
Títí dé, prep. Até. (referindo-se a um local ou espaço).
Títí di, prep. Até. (referindo-se a período de tempo).
Títí  láé, títí láí, adv. Perpetuamente, para sempre, definitivamente.
Títilọ, adv. Continuadamente, assim por diante.

Ń, v. Estar. Indicador de  gerúndio.
Ń, adv. pré-verbal. O prefixo "ń" no verbo indica não só uma ideia presente como uma ação que esteja ocorrendo, em desenvolvimento (gerúndio). Pela sua função, é equivalente ao verbo auxiliar estar em português.
L', pref. No.
L, pref. Forma modificada da palavra ní quando seguida de palavra iniciada por vogal diferente de i.
, prep. Contração da preposição ní e substantivo. Quando a vogal inicial do substantivo não é i, a consoante n da preposição se transforma em l, e a vogal i toma forma de vogal do substantivo posterior. Mas se a vogal do substantivo é i, ela é eliminada. Ní àná ( l'ánàá ). Ní ilé (ní'lé)
, part. enfática. Usada na construção de frases, quando o verbo tiver dois objetos, o segundo objeto é precedido por " ní".
, prep. No, na, em. Usada para indicar o lugar em que alguma coisa está. Indica uma posição estática.
, v. Ter, possuir, dizer.Transportar carga em um barco ou navio. Ocupar, obter, pegar.
Ni, v. Ser, é.
, pron. dem. Aquele, aquela. Requer alongamento da vogal final da palavra que o antecede somente na fala. Ex.: Fìlà ( a ) nì = aquele chapéu.

, v. Bastar, ser o bastante, ser o suficiente. Ser igual a, equivaler.
, adj. Suficiente, bastante.
, pron. rel. Que. Contração de tí ó. A partícula ó é sempre usada se tí for seguida por um verbo. Antes de pronome  e substantivo, ela não é usada. Ọkùnrin tó pè mí ẹ̀gbọ́n mi - O homem que me chamou é meu irmão.
Tó, tóó, adv. pré-v. Antes de. É antecedido por kí. Kí òun tó lọ, ó sọ̀rọ̀ pẹ̀lú mi - Antes de ele ir, eu conversei com ele.

Alátìlẹyìn ẹgbẹ́ òṣèlú, s. Movimento político.
Onírúurú ẹgbẹ́ òṣèlú, s. Vários partidos políticos.
Ẹgbẹ́ alátùn-úntò, s. Reformadores,  grupo reformadores.
Ìwé Ìléwọ́ Àwọn Ẹgbẹ́ Alátùn-úntò Tó Wà Nílẹ̀ Jámánì, s. Manual dos Movimentos de Reforma Alemães.
Àwòrán tí wọ́n fi ń pẹ̀gàn àwọn olóṣèlú, s. Charges políticas.
Ìfiniṣẹlẹ́yà máa ń dá lé, s. Ironia.
Ìfiniṣẹlẹ́yà, s. Zombaria, ironia.
Èébú, s. Insulto, ofensa.
Ẹgbẹ́ ti àwọn Òṣìṣẹ́, s. PT.
Aṣòdì sí Ẹgbẹ́ ti àwọn Òṣìṣẹ́, s. Anti-PT.
Ìṣe Ẹgbẹ́ ti àwọn Òṣìṣẹ́, s. Petismo.
Aṣòdì sí ìṣe Ẹgbẹ́ ti àwọn Òṣìṣẹ́, s. Antipetismo.
Ìròyìn èké, s.Fake news, notícia falsa.
Ìyàsímímọ́, s. Dedicação.