sábado, 10 de novembro de 2018

Sistema nervoso

ÈTÒ Ẹ̀SỌ ARA - O SISTEMA NERVOSO - ARA ENIA - CORPO HUMANO



ÈTÒ Ẹ̀SỌ ARA
O SISTEMA NERVOSO
ENIA
ÀWỌN ÈTÒ Ẹ̀YÀ-ARA
Nível de leitoresPrimário, Secundário, Avançado
by Fakinlede K
VIEW AS PDF
%C3%88%CC%A3YA%20%C3%88%CC%A3S%E1%BB%8C%20ARA%20-%20NERVOUS%20SYSTEM%20-%20%C3%80W%E1%BB%8CN%20%C3%88T%C3%92%20%C3%88%CC%A3Y%C3%80-A%20RA.pdf
PortuguêsYorùbáPortuguêsYorùbá
Nervo Ẹ̀sọSistema nervoso centralÈtò ẹ̀sọ t’ogangan
Célula nervosa (neurônio)Pádi ẹ̀sọSistema nervoso periféricoÈtò ẹ̀sọ t’àgbèègbè
Cordão do nervoÌṣù ẹ̀sọNervo espinhalẸ̀sọ atopayo
Fibra nervosaỌ̀ran ẹ̀sọColuna vertebralỌ̀pá ẹhìn
Raiz nervosaIrìn ẹ̀sọNeurônio
NeurologiaẸ̀kọ́ ẹ̀sọcanal espinhal Ihò ọ̀pá-ẹhìn
NeurologistaOníṣègùn ẹ̀sọ-araAxônio
CérebroỌ̀pọlọDendritos do neurônioIrun ẹ̀sọ
Medula espinhalẹ̀sọ ọ̀pá-ẹhìnNervo motorẸ̀sọ ìmira
Nervo espinhal ẹ̀sọ atọ̀páyọNervos sensoriaisÀwọn ẹ̀sọ-iyè
Neurônio motorPádi ẹ̀sọ-ìmira Nervo autônomo (neurônio) Ẹ̀sọ adáṣiṣẹ́
Neurônio motorPádi ẹ̀sọ-ìmira
O sistema nervoso consiste em células que comunicam informações sobre o entorno de um organismo e sobre si mesmo.Ètò ẹ̀sọ Ara ní àwọn pádi (cell) kan tó njẹ ki ẹ̀dá-oníyè ní ìfura sí àgbèègbè rẹ
O sistema nervoso é dividido em dois sistemas principais, o sistema nervoso central (SNC) e o sistema nervoso periférico. A medula espinal e o cérebro compõem o SNC. Sua principal função é obter as informações do corpo e enviar instruções. O sistema nervoso periférico é composto de todos os nervos e da fiação. Este sistema envia as mensagens do cérebro para o resto do corpo.A pín ètò ẹ̀sọ-ara sí ọnà méjì, ètò ẹ̀sọ t’ọgangan àti ètò ẹ̀sọ t’àgbèègbè. ẹ̀sọ ọ̀pá-ẹhìn àti ọpọlọ ló jẹ́ àpapọ ẹ̀sọ t’ọgangan. Iṣẹ́ rẹ pàtàkì ni gbígba ìhìn (information) láti ara àti láti fi àṣẹ ránṣẹ sí gbogbo ara. Èto ẹ̀sọ t’àgbèègbè ni àwọn ẹ̀sọ gbogbo tó yí inú ara káàkiri bí àwọn (net). Àwọn eléyi ni wọn ngba ìhìn (information) láti ọpọlọ tí wọn si nfi ránṣẹ sí gbogbo ara
Os nervos sensoriais enviam mensagens de partes do corpo, como pele e músculos, de volta à medula espinhal e ao cérebro.Àwọn ẹ̀sọ-iyè ló nṣe ìránṣẹ láti gbogbo ara, bí awọ-ara àti iṣan ara, padà lọ sí ẹ̀sọ ọ̀pá ẹhìn àti ọpọlọ
Os nervos autonômicos controlam funções involuntárias ou semi-voluntárias, como freqüência cardíaca, pressão arterial, digestão, regulação da temperatura e sudorese.Àwọn ẹ̀sọ adáṣiṣẹ́ ló nṣe olùdarí àwọn ẹya-ara tí kò sí lábẹ ìdarí wà. Àwọn nkan bí ìyási sísọ ọkàn, èéfún òpó-ẹ̀jẹ̀, dídà-onjẹ, àtọsọnà ìgbóná ara, àti ìlàágùn.
Os nervos motores enviam impulsos ou sinais do cérebro e da medula espinal para todos os músculos do corpo.Àwọn ẹ̀sọ ìmira (mi ara: move a body part) ló nṣe ìránṣẹ láti ọpọlọ àti ẹ̀sọ ọ̀pá-ẹhìn sí gbogbo àwọn iṣan ara
PortuguêsYorùbáPortuguêsYorùbá
Nervo óptico

Ẹ̀sọ iyè-ìríranNervo sensitivoẸ̀sọ iyè
Nervo acústicoẸ̀sọ ìgbọrọNervo espinhalẸ̀sọ atọ̀páyọ
Fibra nervosa aferente (Nervo aferente)Ẹ̀sọ akọkànNervo vasoconstritorẸ̀sọ afún-ìṣọ̀n
Nervo cranianoẸ̀sọ atoríyọNervo vasodilatadorẸ̀sọ aṣọ-ìṣọ̀n
Fibra nervosa eferente (Nervo eferente)Ẹ̀sọ ìmiraNervo vasomotorẸ̀sọ ìmira-ìṣọ̀n
Nervo olfatórioẸ̀sọ iyè-òórùnNervo oftálmicoẸ̀sọ ìmira-ojú
Nervo secretorẸ̀sọ ẹṣẹ́-araNeurônio motorPádi ẹ̀sọ-ìmira
Fonte: http://yoruba-scipedia.wikidot.com/wiki:ara-enia-human-body-e-ya-e-s-ara-nervous-system

Corpo humano