1. Àwọn àwọ̀ nínú èdè Yorùbá (as cores na língua yorubá):
- Àwọn àwọ̀ àkọ́kọ́ (cores primárias): àwọ̀ dúdú (cor preta), àwọ̀ pupa (cor vermelha) àti àwọ̀ funfun (cor branca).
- Òṣùmàrè (aro-íris). Òṣùmàrè é considerado símbolo de uma divindade representada por uma grande serpente que envolve a terra. "Èyí fi hàn pé ìmọ́lẹ̀ lásán ni gbogbo àwọ̀ méje ara òṣùmàrè, tí wọ́n jẹ́ ní ìtòtẹ̀léra àwọ̀ pupa, olómi ọsàn, ìyeyè, àwọ̀ ewé, búlúù, àwọ̀ aró, àti búlúù rẹ́súrẹ́sú" - "Isso mostra que a luz comum contém todas as sete cores do arco-íris, na ordem: vermelho, laranja, amarelo, verde, azul, índigo e violeta."
- Àwọn àwọ̀ (cores): àwọ̀ ewéko, àwọ̀ ewé (verde), àwọ̀ èsè, àwọ̀ pupa rúsúrúsú, àwọ̀ ìyeyè, àwọ̀ yẹ́lò, àwọ̀ wúrà (cor amarela), àwọ̀ òrom̀bó, àwọ̀ olómi ọsàn, àwọ̀ omi ọsàn (cor laranja), àwọ̀ pípọ́n (cor de âmbar. A cor âmbar é um tom quente, semelhante ao amarelo-alaranjado, que se encontra entre o amarelo e o laranja na roda de cores) , àwọ̀ igi, àwọ̀ ara, àwọ̀ pákó, àwọ̀ ilẹ̀, àwọ̀ búráùn, àwọ búráwùn (marron), àwọ̀ ara (cor da pele), àwọ ayinrin, àwọ̀ búlúù, àwọ̀ aró, àwọ̀ ojú ọ̀run (cor azul), àwọ òféfe, àwọ sánmà (cor azul claro), àwọ ẹlú (cor índigo. O índigo é uma cor que se situa entre o azul e o violeta no espectro de cores, com um tom escuro e profundo), àwọ osùn (cor violeta. A cor violeta é uma cor do espectro visível, localizada entre o azul e o ultravioleta), àwọ osun, àwọ̀ èsè àlùkò, àwọ̀ elésè àlùkò, àwọ̀ àlùkò (cor púrpura, cor roxa), àwọ̀ osùn (cor rosa), àwọ̀ eléérú, àwọ èèrú (cinza), àwọ̀ dúdú (cor preta), àwọ̀ pupa (cor vermelha), àwọ̀ pupa rokoṣo (cor vermelho-forte), àwọ̀ rírẹ̀ dòdò, àwọ̀ rírẹ̀dòdò, àwọ pupayòyò (cor escarlate, cor vermelha muito viva), àwọ̀ iná (cor de fogo), àwọ̀ pípọ́n roro (carmesim, cor vermelha do carmim), àwọ̀ funfun (cor branca), àwọ̀ ìmọ́lẹ̀ (cor da luz), àwọ̀ mèremère (core vibrante), àwọ̀ rẹ́súrẹ́sú mímọ́ (cor clara)
- Àwọn àwọ̀ látinú èdè Gẹ̀ẹ́sì (cores do inglês): búráùn (marrom), búlúù (azul), pópù (roxo), pínkkí (rosa), yẹ́lò (amarelo).
- 2. Ẹ̀yà ọ̀rọ̀ ìsọdipúpọ̀ àwọn àwọ̀ (plural de cores):
- Ìlànà gbogbogbòò kan nínú èdè Potogí (uma regra geral em português):
A regra geral é que as cores que são adjetivos (como azul, vermelho, verde, etc.) concordam em número com o substantivo a que se referem, ou seja, vão para o plural quando o substantivo está no plural. No entanto, cores que são originalmente substantivos (como laranja, rosa, cinza, etc.) e que são usadas para descrever cores, permanecem invariáveis, ou seja, não vão para o plural.
- Gbé àwọn àpẹerẹ tó wà nísàlẹ̀ yìí yẹ̀ wò (veja os seguintes exemplos): àwọn ẹ̀wù aláwọ̀ búlúù (blusas azuis), àwọn ẹ̀wù aláwọ̀ funfun (blusas brancas), àwọn ẹ̀wù aláwọ̀ yẹ́lò (blusas amarelas), àwọn ẹ̀wù aláwọ̀ omi ọsàn (blusas laranja), Àwọn ẹ̀wù aláwọ̀ wáìnì (blusas vinho), àwọn ẹ̀wù aláwọ̀ eérú (blusas cinza), àwọn ẹ̀wù aláwọ̀ wáìnì (blusas vinho).
3. Àwọn ọ̀rọ̀-orúkọ tó tan mọ́ ọn (substantivos relacionados):
Àwọ̀ òkè (cor de primeiro plano), aṣàpèjúwe àwọ̀ (modelo de espaço de cores), ìyàsótò àwọ̀ (separação de cores), àwọ̀ ìkángun (cores análogas), àpótí àwọ̀ (caixa de cores), aláwọ̀ bíìtì-8 (cor de 8 bits), àdàpò àwọ̀ (rampa de cores), dírágónì ńlá aláwọ̀ iná (grande dragão de cor de fogo), ẹranko ẹhànnà aláwọ̀ rírẹ̀dòdò (fera cor de escarlate), ẹranko ẹhànnà ìṣàpẹẹrẹ náà tó ní àwọ̀ rírẹ̀dòdò (a simbólica fera cor de escarlate), tòmátì tó pọ́n fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́ (tomate maduro), òdòdó tó ní àwọ̀ osùn tàbí àwọ̀ funfun (flor cor-de-rosa ou branca), àwọn àwọ̀ fífanimọ́ra ti ìgbà ìwọ́wé (lindas cores do outono), tẹlifíṣọ̀n aláwọ̀ oríṣiríṣi (TV em cores), àwọn àwọ̀ títàn ara aṣọ àwọn Àmẹ́ríńdíà (cores vivas dos indígenas, cores vivas dos trajes dos nativos americanos), ẹ̀wù aláwọ̀ títàn láti Bósírà (vestes de cores brilhantes de Bozra), àwọ̀ yíyani lẹ́nu àwọn igi arẹ̀dànù tí wọ́n ti wọ́wé (surpreendentes cores das árvores decíduas, desnudas de folhas), gbogbo àwọ̀ ara òṣùmàrè (cores do arco-íris), àwọ̀ málamàla títànyòyò (cor viva), àwọn àwọ̀ àrímáleèlọ títàn yòò (cores vivas, cores brilhantes), àwọn àwọ̀ gbígbàfiyèsí (cores atraentes), àwọn àwọ̀ títayọ àti ìrísí kíkọyọyọ (cores sutis e contorno elegante), àwọn aṣọ aláwọ̀ ṣíṣú (roupas de cores escuras), àwọn aṣọ aláwọ̀ títàn (roupas de cores claras).