Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sexta-feira, 23 de dezembro de 2011

Evocação do tempo

›
   Evocação do tempo 1. Mo júbà àkọ́ dá. Eu saúdo os primórdios da existência. 2. Mo júbà aṣẹ̀ dá. Saúdo o criador. 3. Àtiy ọ̀ ...
Um comentário:

SAUDAÇÕES E CUMPRIMENTOS

›
Ìkíni àti ìpàdé (saudações e cumprimentos) - Ẹ́  káàár ọ  sà, p ẹ̀lẹ́ . Sé dáadáa l'o ji? Bom dia senhor, olá. Será que bem esta...
Um comentário:

CANTIGA DE EXÚ

›
A pàdé  ọ lọ́ọ̀ na, ẹ  mo júbà òjíṣẹ́ , àwa ṣ e awo, àwa ṣ e awo, àwa  ṣ e awo. Mo júbà òjíṣẹ́. Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário) Àkójọ́p...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.