Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

domingo, 8 de junho de 2014

Política de ações afirmativas

›
Àwọn alápakán láìlọ́pẹ́ Os cotistas desagradecidos. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário)   Alápakán  = ...
sábado, 7 de junho de 2014

Físíksì kùátọ̀mù.

›
Láti Físíksì kùátọ̀mù dé  ohun ti ẹ̀mí . Da Física Quântica à Espiritualidade. Àkój ọ́ p ọ̀  Itum ọ̀  (Glossário). Ìwé gbédègbéy ọ̀ ...

Ẹ̀sìn Búddà ( budismo)

›
Àwòrán  lẹwa kan! Uma imagem linda! Àkój ó p ò   Itum ò   (Glossário). Ìwé gbédègbéy ò   (Vocabulário) Àwòrán = quadro, retrato, i...

Guiné-Bissau

›
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Guinea-Bissau: ara-ìrànlọ́ w ọ́  fún àlàáfíà. República da Guiné-Bissau: Auto-ajuda para a paz. Àkój ó...

Plantas aquáticas

›
   "Ojú oró ni í lékè omi.   Ojú oró está sobre a água.  Òsíbàtà ni í lékè odò. Òsíbàtà está sobre o rio. Fìlà ni í lékè orí. ...
terça-feira, 3 de junho de 2014

Copa do mundo de futebol

›
Ìmọ tótó ti è yà  ènìyàn  fún i fe-ẹ̀yẹ àgbáyé bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀. Limpeza étnica para copa do mundo de futebol. Àkój ó p ò   Itum ò   (...
segunda-feira, 2 de junho de 2014

Ẹ́kísódù ( Êxodo) 20:1-26

›
Ẹ́kísódù ( Êxodo) 20:1-26  Ìtúmọ̀:  Olùkọ́ Orlandes  Texto bíblico para aprender yorubá e somente yorubá, o idioma dos orixás e do cand...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.