Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quarta-feira, 30 de julho de 2014

Astrônoma afro-brasileira

›
Atòràwọ̀ Ọmọorílẹ̀-èdè Bràsíl. Astrônoma brasileira. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). Ìràwọ̀ , s. Estr...

Filosofia oriental

›
                                                                                      1 - Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ará ilẹ̀ Ṣáínà.        Rep...

Feliz aniversário!

›
Bíbáyọ̀ fún ọ , ọmọ ìsàmì obìnrin mi! Parabéns para você, minha afilhada! Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabul...
terça-feira, 29 de julho de 2014

Luta Guarani!

›
  Ìjà guaraní.   Luta Guarani.                                                                                   Jaraguá ni Ọgbà ...
segunda-feira, 28 de julho de 2014

Na Rota dos Orixás

›
Ní ipa ti àwọn Òrìṣà. Na Rota dos Orixás. Ìwé gbédègbéy ò   ( vocabulário) Àkój ó p ò  ìtúm ò  ( Glossário). Ní, prep...

México

›
    Àwọn Ìpínlẹ̀ Mẹ́ksíkò Aṣọ̀kan.   Estados Unidos Mexicanos. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). Àwọn, wọ...

Monstros

›
  Abàmì ẹran gíga. Monster High. Monstro alta.                                                                      Àkój...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.