Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quarta-feira, 28 de janeiro de 2015

O operário em construção

›
    Nítorí náà ó mú un gòkè wá, ó sì fi gbogbo ìjọba ilẹ̀ ayé tí a ń gbé hàn án ní ìṣẹ́jú akàn; Sátánì sì wí fún un pé: “Gbogbo ọlá àṣẹ yì...
segunda-feira, 26 de janeiro de 2015

Diálogo entre Deus e Dilma Rousseff sobre genocídio indígena.

›
     Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run  sọ fún  Ààrẹ Dilma Rousseff  pé: “Ibo ni  Adenilson Munduruku ará ìlú  kannáà  rẹ wà?” òun sì sọ pé: “Èmi kò mọ̀....

Cidadania brasileira

›
  Irú mẹ́ta ọmọ ìlú ní ilẹ̀ Bràsíl. Três tipos de cidadãos no Brasil. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). Irú ...

Homo sapiens

›
Tani àwọn ọmọnìyàn? Quem são os humanos? Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). Tani , pron. interrog. Quem....
sexta-feira, 23 de janeiro de 2015

Homo sacer brasileiro

›
Ọmọnìyàn mímọ́ ọmọorílẹ̀-èdè Bràsíl. Homo sacer brasileiro. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). Ọmọnìyàn m...
terça-feira, 20 de janeiro de 2015

Hino nacional brasileiro em guarani

›
  Orin-ìyìn Onítọmọorílẹ̀-èdè Bràsíl ní èdè Guaraní. Hino nacional brasileiro em guarani. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbé...

Cantando para Nhanderú

›
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.