Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quarta-feira, 21 de outubro de 2015

Os paleoíndios negros na pré-história do continente americano.

›
Àwọn onílẹ̀-ayéijọ́un dúdú ní ìṣíwájú ìtàn  ti orílẹ̀ Amẹ́ríkà. Os paleoíndios negros na pré-história do continente americano.           ...
terça-feira, 20 de outubro de 2015

Família Obama

›
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà àti ẹbí rẹ. Presidente dos Estados Unidos e sua família. Ìyálóde ti  Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà Primeira-...
segunda-feira, 19 de outubro de 2015

Renascimento africano

›
          Ìtúnṣe Áfríkà (renascimento africano)    A Renascença Africana é um conceito de que o povo e as nações da África devem superar ...

Genocídio no Brasil carinhoso

›
1.   Olórí guaraní Kaiowá kìlọ̀ ìfẹjú ti aṣòfin àpapọ̀  ní Ilé Aṣòfin Kéreré.   Liderança Guarani Kaiowá denuncia ameaça de deputado fede...
sábado, 17 de outubro de 2015

Michele Obama

›
Ìyálóde ti  Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà Primeira-dama dos Estados Unidos da América. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀...

Mãe

›
      Ìyá, màmá, yé, yèyé (mãe) Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). 1.Ìyá ńlá (avó. Nome dado à grande pro...
quarta-feira, 14 de outubro de 2015

Ranking mundial das Universidades 2015

›
Ẹ ó  mọ òtítọ́, òtítọ́ yóò sì dá yín sílẹ̀ lómìnira ( Jòhánù 8:32)  .   Vocês conhecerão a verdade, e a verdade os libertará ( João 8:32)...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.