Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quarta-feira, 8 de março de 2017

Pronome reflexivo

›
Ọ̀rọ̀ arọ́pò orúkọ láròjinlẹ. Pronome reflexivo. 1. Ti ènìyàn kan (singular) Ara mi = eu mesmo Ara rẹ = você mesmo)  Ara rẹ̀ = ele m...

Pronome objeto (oblíquo)

›
Ọ̀rọ̀ arọ́pò orúkọ tí a fi lẹ́hìn ti ọ̀rọ̀ ìṣe pẹ̀lú agbára àṣekún tàbí igbákéjì.  Pronome objeto (oblíquo) 1. Ti ènìyàn kan (singular)...

Pronome possessivo (ênfase)

›
Ọ̀rọ̀ arọ́pò orúkọ fí ìní (ìtẹnumọ́). Pronome possessivo (ênfase). 1. Ti ènìyàn kan (singular) Tèmi = meu, minha Tirẹ   = de você Ti...

Pronome possessivo

›
Ọ̀rọ̀ arọ́pò orúkọ fí ìní Pronome possessivo. 1. Ti ènìyàn kan (singular) Mi = meu, minha Rẹ = de você Rẹ̀ = dele, dela 2. Ti ènì...

Pronome pessoal com advérbio

›
Ọ̀rọ̀ arọ́pò orúkọ ti ara ẹni pẹ̀lú adífábù. Pronome pessoal com advérbio. 1. Ti ènìyàn kan (singular) Mà = eu Wà = você Á = ele, el...

Pronome pessoal

›
Ọ̀rọ̀ arọ́pò orúkọ ti ara ẹni. Pronome pessoal. 1. Ti ènìyàn kan (singular) Mo, mi, ng = eu  O = você Ó = ele, ela                 ...

Pronome pessoal (ênfase)

›
Ọ̀rọ̀ arọ́pò orúkọ  ti ara ẹni (ìtẹnumọ́) Pronome pessoal (ênfase) 1. Ti ènìyàn kan (singular)                                         ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.