Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sexta-feira, 7 de julho de 2017

Plantas

›
Ewé kódìí-kódìí.

Galináceos

›
Ẹ̀yà ara àti orúkọ tí à ń pe ẹdìẹ akọ àti  abo. Nomes de partes do corpo  de galináceos machos e fêmeas.

Quem somos nós?

›
                                                            Ta ni àwa? Quem somos nós?  Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gb...

Física quântica

›
Orí  inú  ti ẹ̀dà èèyàn àti àgbáálá ayé náà. A mente humana e o Universo.                                                               ...
quinta-feira, 6 de julho de 2017

Teoria da evolução

›
Èrò ìjìnlẹ̀ sìntẹ́tíkì  ti ìtirànya àti  ìwọ̀ntúnwọ̀nsì ṣe gẹ́.   Teoria Sintética Evolutiva e Equilíbrio Pontuado.                       ...

Amit Goswami

›
     Físíksì kúántù (Física quântica) 1.Ìjàjagbára kúántù (ativismo quântico)            2. Sáyẹ́nsì àti ohun ti ẹ̀mí (ciência...

Centenas de milhares.

›
 Láwọn orílẹ̀-èdè kan àwọn abọ̀rìṣà tó wà níbẹ̀ lé ní ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọ́rùn-ún.  Em alguns países, existem centenas de milhares de devo...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.