Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

segunda-feira, 24 de julho de 2017

Prefeitura de São Paulo

›
Àṣẹ ti  gbọ̀ngàn ìlú  láti wó ilé alájà pẹ̀lú àwọn  olùgbé ní inú. Ordem da Prefeitura para demolir prédio com moradores dentro dele.    ...

Um golpista vampiro na presidência do Brasil

›
                                                            Ìdìtẹ̀ gbàjọba ńṣe pípa ẹ̀yà ìran run  ní'lẹ̀ Bràsíl . Golpe faz a limpez...

Jean Wyllys

›
Àwọn ìbéèrè fún Aṣòfin àpapọ̀ Jean Wyllys.  Perguntas para o Deputado Federal Jean Wyllys.                                                ...

Consciência negra

›
Ó fi àpẹẹrẹ tó tayọ lélẹ̀ tó bá dọ̀rọ̀ ká nífẹ̀ẹ́ orílẹ̀ Áfríkà pẹ̀lú gbogbo ọkàn wa, gbogbo ẹ̀mí wa, gbogbo èrò-inú wa àti gbogbo okun wa....
domingo, 23 de julho de 2017

Higiene

›
Ìmọtótó ló lè ṣẹ́gun àrun o. A limpeza pode vencer a doença! . Ìmọtótó ilé ( Limpeza da casa). Ìmọtótó ara ( Limpeza do corpo). Ìmọtót...

Exu

›
A pàdé  ọ lọ́ọ̀ na, ẹ  mo júbà òjíṣẹ́ , àwa ṣ e awo, àwa ṣ e awo, àwa  ṣ e awo. Mo júbà òjíṣẹ́. Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário) Àkójọ́pò...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.