Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

terça-feira, 25 de julho de 2017

Orin Ogum

›
Ògún yè, pàtàkì orí Òrìṣà. Salve Ogum, Orixá importante da cabeça! Ògún àjò e màrìwò, Alákòró  ajò ẹ màrìwò. Ògún pa lè pa  l'ọ́n...

Orin Exu

›
 Èṣù yè, Laróyè! (Viva Exu! ou Salve Exu!)  1. Ẹ̀yà àṣẹ̀ṣẹ̀jáde kíní (primeira versão)       Ójíṣẹ́ pa'lé fún awo, Ọ̀dàrà  p...

Orin Oxum

›
Rọra Yèyé ó fi adé rí ọmọ.                                       Mãe cuidadosa, aquela que usa coroa e olha seus filhos.  Orin Ọ̀ṣùn (cant...

Orin Exu

›
Èṣù yè, Laróyè! (Viva Exu! ou Salve Exu!) A pàdé Ọlọ́nà e mo júbà  Ójíṣẹ́. Vamos encontrar o senhor dos caminhos. Meus respeitos àqu...

Orin Oxum

›
Rọra Yèyé ó fí adé rí ọmọ.                                       Mãe cuidadosa, aquela que usa coroa e olha seus filhos.  Aládé Ọ...

Submarino

›
Bí àpẹẹrẹ, lọ́dún 1915, àwọn ará Jámánì ti bẹ̀rẹ̀ sí í fi ọkọ̀ abẹ́ omi rìn káàkiri inú omi òkun tó yí ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ká. Por exemplo, em 1...
segunda-feira, 24 de julho de 2017

Prefeitura de São Paulo

›
Àṣẹ ti  gbọ̀ngàn ìlú  láti wó ilé alájà pẹ̀lú àwọn  olùgbé ní inú. Ordem da Prefeitura para demolir prédio com moradores dentro dele.    ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.