Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sexta-feira, 28 de julho de 2017

Justiça

›
                                                                Onídájọ́ pè ọmọbìnrin láti ṣe ìdájọ́ ìyá tòun náà. Moríwù! Juiz chama fil...

Feminismo negro

›
Ọ̀rọ sísọ náà ṣe ń lọ lọ́wọ́.   Palestra ao vivo.                                                               Angela Davis, no Brasil...
quinta-feira, 27 de julho de 2017

Igreja católica

›
Àwọn ọ̀rọ̀ orùkọ díẹ̀ àti ìtúmọ̀ wọn. Alguns nomes e seus significados. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário)...
quarta-feira, 26 de julho de 2017

Carnaval

›
Ní ìgbà ayẹyẹ ìlú, màá múra bí obìnrin, màá sì máa jó nígbà táwọn ọmọ ilé ijó sáńbà bá ń jó kọjá níwájú àwọn èèyàn. No carnaval, eu me ve...
terça-feira, 25 de julho de 2017

Orin Ogum

›
Ògún yè, pàtàkì orí Òrìṣà. Salve Ogum, Orixá importante da cabeça! Ògún àjò e màrìwò, Alákòró  ajò ẹ màrìwò. Ògún pa lè pa  l'ọ́n...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.