Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sexta-feira, 3 de novembro de 2017

Telefone celular.

›
Ó máa ń lo fóònù rẹ̀ láti lọ sórí ìkànnì Íńtánẹ́ẹ̀tì tó ti lè rí àwòrán oníhòòhò. Ele começou a usar o celular para acessar sites pornogr...
segunda-feira, 30 de outubro de 2017

Interjeição

›
  À mì ìyanu: ponto de exclamação (!) Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). Eèpàà!, eèpàrìpàà! , interj. ...
sábado, 28 de outubro de 2017

OPEP

›
Àjọ Àwọn Orílẹ̀-Èdè Tó Ń Ta Epo Sílẹ̀ Òkèèrè (OPEC). Organização dos Países Exportadores de Petróleo (OPEP). Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossár...
sexta-feira, 27 de outubro de 2017

Pai nosso

›
       Àdúrà  bàbá  wa.      Oração do pai nosso.                                                                               "Bab...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.