Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

terça-feira, 14 de novembro de 2017

Filosofia africana

›
Àwọn fídíò lórí filọ́sọ́fi  ti Áfríkà. Vídeos sobre filosofia africana. 1. A dimensão ético-política de Ubuntu: Uma proposta para a super...

Religiões afro-brasileiras

›
Àwọn ẹ̀sìn Áfíríkà-Bràsíl fẹ́ ṣe ẹjọ́ Orílẹ̀-Èdè náà ní Ilé ẹjọ́ Àjọdá ti Amẹ́ríkà. As religiões afro-brasileiras querem processar o Esta...

Ifá

›
Ǹjẹ́ Ifá dáhùn àwọn ìbéèrè nípa ohun tó ti ṣẹlẹ̀ kọjá, àwọn ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́, àtàwọn ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú? Será que ...

Deuses da natureza

›
Òǹkọ̀wé kan sọ pé: “Òòṣà abo àti Ọlọ́run ni wọ́n máa ń wò bí àpẹẹrẹ àwọn takọtabo ẹ̀dá ayé  Certo escritor diz: “A Deusa e o Deus são enca...

Parapsicologia

›
Àwọn ìwé, eré ìdárayá, eré orí tẹlifíṣọ̀n, àtàwọn sinimá tó ń gbé iṣẹ́ oṣó àti àwọn ohun abàmì lárugẹ, sì tún wá pọ̀ lọ jàra. Nunca houve...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.