Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quarta-feira, 15 de novembro de 2017

Escravidão contemporânea

›
Díẹ̀ lára àṣà ìfiniṣẹrú táa mọ̀ láyé ìsinyìí ni fífipá kó èèyàn ṣiṣẹ́, lílo ìyàwó bí ẹrú, fífini sọfà, kíkó ọmọdé ṣiṣẹ́, àti lọ́pọ̀ ìgbà kí...

Politicagem

›
                                                            Àwọn ọgbọ́n àrékérekè ti Ààrẹ Fanpaya. Politicagens do Presidente Vampiro. ...
terça-feira, 14 de novembro de 2017

Filosofia africana

›
Àwọn fídíò lórí filọ́sọ́fi  ti Áfríkà. Vídeos sobre filosofia africana. 1. A dimensão ético-política de Ubuntu: Uma proposta para a super...

Religiões afro-brasileiras

›
Àwọn ẹ̀sìn Áfíríkà-Bràsíl fẹ́ ṣe ẹjọ́ Orílẹ̀-Èdè náà ní Ilé ẹjọ́ Àjọdá ti Amẹ́ríkà. As religiões afro-brasileiras querem processar o Esta...

Ifá

›
Ǹjẹ́ Ifá dáhùn àwọn ìbéèrè nípa ohun tó ti ṣẹlẹ̀ kọjá, àwọn ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́, àtàwọn ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú? Será que ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.