Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quinta-feira, 23 de novembro de 2017

Amazônia

›
Àwọn ọmọ ogun Amẹ́ríkà lè gbógunlọ sí    Amasónìà ní ọjọ́ iwájú.  Fún  èyí, wọ́n ńgbà  ìkẹ̀kọ́ ológun  ní ilẹ̀ Bràsíl. Tropas dos EUA pode...
quarta-feira, 22 de novembro de 2017

Ìdánwò mẹ́rin (ọdún kéjì)

›
Nome                                                                 Nº       Série                                                        ...
terça-feira, 21 de novembro de 2017

Ìdánwò mẹ́rin (ọdún kẹ́ta)

›
Nome                                                              Nº         Série                           PROVA DE FILOSOFIA          ...
sábado, 18 de novembro de 2017

Sem

›
Àwọn ẹlẹ́kọ̀ọ́ ẹfolúṣọ̀n ṣàlàyé bí ìwàláàyè ṣe bẹ̀rẹ̀  lórí ilẹ̀ ayé, àmọ́ wọn ò gbà pé Ọlọ́run ló ṣẹ̀dá ohun gbogbo. A teoria da evoluçã...

Sem-teto

›
Àwọn ìṣòro ìgbé ayé ẹ̀dá tó ti ta gbòǹgbò, bí àìrílégbé àti òṣì ṣòro mú kúrò pátápátá. Problemas sociais que já existem há muito tempo, c...
quarta-feira, 15 de novembro de 2017

Escravidão contemporânea

›
Díẹ̀ lára àṣà ìfiniṣẹrú táa mọ̀ láyé ìsinyìí ni fífipá kó èèyàn ṣiṣẹ́, lílo ìyàwó bí ẹrú, fífini sọfà, kíkó ọmọdé ṣiṣẹ́, àti lọ́pọ̀ ìgbà kí...

Politicagem

›
                                                            Àwọn ọgbọ́n àrékérekè ti Ààrẹ Fanpaya. Politicagens do Presidente Vampiro. ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.