Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quarta-feira, 13 de dezembro de 2017

Tudo vai ficar bem!

›
Gbogbo àwọn ọ̀ ràn ọ̀hún á yanjú ! Tudo vai ficar bem!  Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). Gbogbo ...

Redes sociais

›
Ọ̀gá pátápátá tẹ́lẹ̀ ti Ojúìwé  ń dámọ̀ràn  pé o ṣì fi ọ̀rọ̀ yẹn sílẹ̀ ná lórí àwọn ìkànnì àjọlò. Ex-executivo do Facebook recomenda que v...
terça-feira, 12 de dezembro de 2017

Paneleiro

›
Ohun ìránnilétí fún ẹni tí ó lù ìkòkò ìseńjẹ  ti lọ. Monumento ao paneleiro desaparecido. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbéd...

Hackers invadem site da Previdência social

›
Àwọn ẹ nì kan tó máa ń fọgbọ́n jí ìsọfúnni nínú kọ̀ǹpútà àwọn ẹni ẹlẹ́ni jí ìsọfúnni ì kànnì ti  ààbò àwùjọ. Hackers invadem site da Pre...

Organizações terroristas

›
Àkójọ ti àwọn ẹgbẹ́  apániláyà 148 tí ó wà ní àyíká à gbáyé .  Lista de 148 organizações terroristas em todo o mundo. 1. AL-Shabab (Áfr...
terça-feira, 5 de dezembro de 2017

Fases do desenvolvimento humano.

›
Àwọn ìgbà ti ìdàgbàsókè ẹ̀dà èèyàn. As fases do desenvolvimento humano. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário)...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.