Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quarta-feira, 17 de janeiro de 2018

Pan Africanismo e Afrocentricidade

›
                                                                  Kwame Ture e Molefi Asante - Ìṣe pan-áfríkánístì àti ẹ̀kọ́ nípa alárin-Á...
segunda-feira, 15 de janeiro de 2018

Supermercado do Jornal nacional

›
Ilé ìtajà ńlá ti ìròyìn orí tẹlifíṣọ̀n  to rílẹ̀-èdè. Supermercado do Jornal nacional.  Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbé...
domingo, 14 de janeiro de 2018

Direito personalizado

›
Àwọn òfin àkànṣe fún  irú  ọ̀kọ̀ọ̀kan  ti  ọ mọorílẹ̀-èdè Bràsíl. Ní'l ẹ̀ Bràsíl,  òfin  kì í ṣe fún gbogbo ènìyàn Leis personalizad...
segunda-feira, 8 de janeiro de 2018

Geografia

›
Onímọ̀ Jẹ́ọ́gráfì ọmọorílẹ̀-èdè Nàìjíríà gbà "Ẹ̀bùn Nobel ti Jẹ́ọ́gráfì. Geógrafo nigeriano vence "Prêmio Nobel de Geografia...
sábado, 6 de janeiro de 2018

Os três turnos da eleição de 2018

›
Nígbà tó di ọdún 2018, a á dìbò yan nígbà mẹ́ta fún àwọn tó fẹ́ di Ààrẹ ti ilẹ̀ Bràsíl. Em 2018, vamos votar três vezes para candidatos à ...

Ajogun

›
Èṣù (Exu) Divindade com diferentes atributos ligados à comunicação entre o céu e a Terra, aos caminhos e à fertilidade. Oríkì Èṣù ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.