Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sexta-feira, 19 de janeiro de 2018

Doenças

›
A óò mú àìsàn, ìbànújẹ́ àti ikú pàápàá kúrò. Eliminar-se-ão a doença, a tristeza e até mesmo a morte. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìw...
quinta-feira, 18 de janeiro de 2018

A pobreza nos Estados Unidos

›
                                                        Èyí ni ìpínlẹ̀ Kalifọ́rníà pẹ̀lú apá kan ti àwọn ogójì mílíọ́nù a kúṣẹ́  tó ń gbé ...

A Ciência do Vodun

›
                                                            Sáyẹ́nsì  ti fúdù. A ciência do vodun (vodu, voodoo).                    ...
quarta-feira, 17 de janeiro de 2018

Pan Africanismo e Afrocentricidade

›
                                                                  Kwame Ture e Molefi Asante - Ìṣe pan-áfríkánístì àti ẹ̀kọ́ nípa alárin-Á...
segunda-feira, 15 de janeiro de 2018

Supermercado do Jornal nacional

›
Ilé ìtajà ńlá ti ìròyìn orí tẹlifíṣọ̀n  to rílẹ̀-èdè. Supermercado do Jornal nacional.  Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbé...
domingo, 14 de janeiro de 2018

Direito personalizado

›
Àwọn òfin àkànṣe fún  irú  ọ̀kọ̀ọ̀kan  ti  ọ mọorílẹ̀-èdè Bràsíl. Ní'l ẹ̀ Bràsíl,  òfin  kì í ṣe fún gbogbo ènìyàn Leis personalizad...
segunda-feira, 8 de janeiro de 2018

Geografia

›
Onímọ̀ Jẹ́ọ́gráfì ọmọorílẹ̀-èdè Nàìjíríà gbà "Ẹ̀bùn Nobel ti Jẹ́ọ́gráfì. Geógrafo nigeriano vence "Prêmio Nobel de Geografia...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.