Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

terça-feira, 27 de fevereiro de 2018

Favelados e negros são fotografados pelo exército brasileiro

›
Àwọn àmì ti ìwà ìkà násì. Símbolos da barbárie Nazista. 1.  "Estrela de judeu", símbolo de discriminação e morte. Há...
domingo, 25 de fevereiro de 2018

Bandido bom é bandido morto

›
Ọ̀dáràn rere jẹ́ ọ̀dáràn kan tó ti kú. Bandido bom é bandido morto. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário)...

Objetivos dos três poderes do golpe

›
Àwọn ète ti agbára mẹ́ta náà nínú ti ìdìtẹ̀ gbàjọba.   Objetivos dos três poderes dentro do golpe de Estado. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glos...
sábado, 24 de fevereiro de 2018

Intervenção federal no Rio de Janeiro

›
Àwọn ọmọdé tálákà àti adúláwọ̀ tí a yẹ̀wò nípasẹ̀ ẹgbẹ́ ọmọ ogun ní'lùú Rio de Janeiro. Criancinhas pobres e negras são revistadas p...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.