Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

terça-feira, 13 de março de 2018

Justiça eleitoral.

›
Ìdájọ̀ òdodo tó ń pinnu lórí ìdìbòyàn. Justiça eleitoral. A Justiça Eleitoral brasileira é um ramo especializado do Poder Judiciário, co...
segunda-feira, 12 de março de 2018

Kapparot

›
  Lọ́jọ́ Ètùtù, àlùfáà àgbà máa ń rú ẹbọ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn èèyàn.—LÉFÍTÍKÙ 16:15, 29-31. No Dia da Expiação, o sumo sacerdote oferecia um...
sexta-feira, 9 de março de 2018

Campanha presidencial de 2018

›
Ìpolongo tí ààrẹ orílẹ̀-èdè. Campanha presidencial. Mo jẹ́rí pé ìmọ́lẹ̀ ti òtítọ́  kò lè ṣeé pa. Eu testifico que a luz da verdade ...
quinta-feira, 8 de março de 2018

Vá pra Cuba!

›
O lè máa lọ sí Kúbà!  Você pode ir pra Cuba!                                                           Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário)....
quarta-feira, 7 de março de 2018

Ète lórí ẹrí-ọkàn dúdú.

›
Ète lórí  ẹrí-ọkàn dúdú. Projeto consciência negra.                Ní sáà ilé ẹ̀kọ́ ti ọdún 2018                Durante o ano letivo de...

Èrò ẹ̀kọ́ ti ọdún kẹ́ta - 2018

›
Èrò ẹ̀kọ́ ti ọdún kẹ́ta - 2018 Plano de ensino do terceiro ano - 2018. Primeiro Bimestre                            SECRETAR...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.