Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

domingo, 29 de abril de 2018

Telejornal

›
                                                    Ìròyìn Orí Tẹlifíṣọ̀n (telejornal). Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀...

Supremo Tribunal Federal

›
Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè tí kò ṣe ìgbọ́ràn sí òfin Ilé-ẹjọ́ Gígajùlọ. Cidadãos que não obedecem às leis do Supremo Tribunal Federal. Brasi...

Coréia do Norte

›
  Kòréà Àríwá tí àwọn tẹlifíṣọ̀n kò fihàn! A Coréia do Norte que as TVs não mostram! Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  ...

Agradecimento

›
Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ àwọn ẹni bí ẹni èèyàn bí èèyàn tó f'ọ̀rọ̀ ránṣẹ́ sí 'mi àtàwọn tó pèmí fún àṣeyẹ àná, ohun ire la ó máa bára wa ṣe ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.