Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quarta-feira, 27 de junho de 2018

TPNPB

›
  Ọmọ Ogun Òmìnira Torílẹ̀-èdè ti Apáìwọ̀òrùn Papua. Exército de Libertação Nacional de Papua Ocidental (TPNPB). . https://tpnpbnew...

Capital yorubá das Américas

›
  Ìpínlẹ̀ Bahia yóò di  Olúìlú yorùbá ti àwọn ilẹ̀ Amẹ́ríkà.    Bahia será capital yorubá das Américas. . http://www.liciafabio.com...
segunda-feira, 25 de junho de 2018

As abominações da classe média.

›
Àwọn ìwà ìríra tó ń wà nínú ti  ẹgbẹ́ àrin . As abominações da classe média. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabu...
sábado, 23 de junho de 2018

Haiti

›
Ọjọ́ yẹn ni ìmìtìtì ilẹ̀ tó runlérùnnà wáyé lórílẹ̀-èdè Hàítì . Naquele dia, um terremoto catastrófico atingiu o Haiti. Àkójọ́pọ̀ It...
quinta-feira, 21 de junho de 2018

A seleção brasileira

›
Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ti àwọn òmùgọ̀  òkúùgbẹ́  ti orílẹ̀ èdè Bràsíl!                             A seleção dos vira-latas brasileiro...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.