Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sábado, 14 de julho de 2018

Sibéria

›
A máa mú ẹ lọ sí àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́, a ó sì kó àwọn yòókù lọ sí àgbègbè  Sìbéríà ! Você vai para um campo de prisioneiros, e os outros v...

Cientista africano

›
Iṣẹ́ -  onímọ̀ ìṣirò àti  onímọ̀ sáyẹ́ǹsì  kọ̀ǹpútà. Profissão – matemático e cientista da computação.                 Phillip Emeagwali...
sexta-feira, 13 de julho de 2018

Márcia

›
  Láìsí àní-àní, Márcia máa rí ojútùú kan fún àwọn àrùn tí Jésù kò lè ṣèwòsàn.  Com certeza, Márcia encontrará uma solução para as doença...
segunda-feira, 9 de julho de 2018

Fezes

›
O yẹ kí o fún ìtúdànù omi sínú ilé ìyàgbẹ́ lẹ́yìn o ṣu ìgbọ̀nsẹ̀ rẹ .   Dê descarga após fazer seu bolsonaro. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glo...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.