Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sexta-feira, 20 de julho de 2018

Universidade

›
Yunifásítì Tẹknọ́lọ́jì Àpapọ̀ ilú Àkúrẹ́. Universidade Federal de Tecnologia, Akure. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (V...

Movimento feminista

›
A jẹ́  àwọn ọmọ ọmọ ti  gbogbo  à jẹ́  tí kò lè fi iná sun.    Somos as netas de todas as bruxas que não conseguiram queimar. A bruxaria...

Aporofobia

›
Ìkórìíra fún àwọn òtòṣì túmọ̀ ilẹ̀ Bràsíl náà lẹ́yìn ìdìtẹ̀ gbàjọba.    Aporofobia, a aversão aos pobres, define o Brasil pós-golpe. ...
quinta-feira, 19 de julho de 2018

Lula livre!

›
                                                            Àwa ọmọ ogun fún Lula di òmìnira . Nós somos guerreiros por Lula livre. ...
segunda-feira, 16 de julho de 2018

Mouros

›
Ní ọdún 1492, àwọn ọmọ ogun Kátólíìkì tí wọ́n ń jà fún Ọba Ferdinand àti Ọbabìnrin  Èlísábẹ́tì ṣẹ́gun àgbègbè tó kẹ́yìn níbi tí àwọn Mùs...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.