Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

segunda-feira, 23 de julho de 2018

Lula livre

›
  Ìjọ Kátólíìkì Áńgílíkà yóò wọnú Ilé-ẹjọ́ Gígajùlọ (STF) pẹ̀lú ẹ̀bẹ̀ Ààbò lábẹ́ òfin lòdì sí ẹ̀wọ̀n tí kò tọ́ fún Lula.       A Igreja Ca...

Música.

›
                                                              Àwọn ọmọdé ò sì yéé sọ pé ká fi fídíò han. As crianças ainda nos pedem para...
domingo, 22 de julho de 2018

Abate religioso de animais

›
Láti ìgbà ayé Ébẹ́lì wá làwọn ẹni ìgbàgbọ́ ti máa ń fi àwọn ẹran rúbọ sí Ọlọ́run. Homens fiéis, a partir de Abel, ofereceram sacrifícios d...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.