Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sexta-feira, 3 de agosto de 2018

Rap

›
Àwòrán Bolsonaro kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà  ti dénú orin ọlọ́rọ̀ wótòwótò, wọ́n sì ti gbẹ́ ẹ ní ère sáwọn ìlú ńlá, kódà wọ́n ń jó ijó rẹ̀. A imagem d...
quarta-feira, 25 de julho de 2018

Dia da mulher negra

›
Ọjọ́ tí a júbà fún obìnrin dúdú. Dia da mulher negra. Mo kí ẹ kúu ti ọjọ́ tí a júbà fún obìnrin dúdú! - Parabéns pelo dia da mulher n...
terça-feira, 24 de julho de 2018

Filosofia africana

›
Ìmọ̀ ọgbọ́n orí Áfríkà (filosofia africana)                                                Estudos Africanos : Katúscia Ribeiro e Aza Nj...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.