Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

terça-feira, 21 de agosto de 2018

Superioridade intelectual dos nordestinos

›
Ilọlájù lóye ti àwọn ọmọ ìhà àríwá ìlà oòrùn. Superioridade intelectual dos nordestinos. Alunos do Nordeste levam 59 das 75 medalhas...

Essência

›
Sọ kókó ọ̀rọ̀ náà fún mi. Conte-me a essência daquele assunto. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). Afisọ̀...
segunda-feira, 20 de agosto de 2018

Queremos que a Interpol prenda o juiz Sergio Moro!

›
Ọlọ́pàá àgbáyé ń ṣàgbéyẹ̀wò ìwà ti adájọ́ Sérgio Moro, ó sì ń rí ìṣísẹ̀ rẹ̀ gbogbo. A polícia internacional observa a conduta do juiz Serg...

O arquétipo de Lúcifer na corrida presidencial

›
                    Lúsíférì ń lo ọ̀pọ̀ ìdẹkùn. O  Lúcifer  usa muitas armadilhas. . Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbé...

Basílica

›
Ṣọ́ọ̀ṣì Ńlá ti Pétérù Mímọ́ ní Róòmù. Basílica de São Pedro, em Roma. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.