Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

segunda-feira, 3 de setembro de 2018

União dos Coletivos Pan Africanistas.

›
Ìṣọ̀kan ti Àwọn Ẹgbẹ́ Gbogbo  Ọ mọ Áfríkà. União dos Coletivos Pan Africanistas. Tó o bá fẹ́ àlàyé síwájú sí i (para saber mais): ...

O Fóssil de Luzia

›
Ìpakúpa ìkẹyìn náà ti àwọn aláwọ̀dúdú ará Bràsíl  tún dé bá  eegun agbárí Lùsíà (ọmọbìnrin ilẹ̀ Bràsíl àkọ́kọ́ náà).  Ó ti ní ikú kejì kan ...

O crânio de Luzia

›
Ajẹ́rìíkú àkọ́kọ́ ti ìṣeọ̀rọ̀ayéijọ́un tó tíì gbé lórílẹ̀-èdè Bràsíl. A primeira mártir da arqueologia brasileira. Luzia causava ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.