Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quinta-feira, 20 de setembro de 2018

Mulheres que voam

›
Àwọn obìnrin tó ń fò ní agbedeméjì ọ̀run. Mulheres que voam no meio do céu. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulár...
quarta-feira, 19 de setembro de 2018

Filosofia africana

›
                                                        Filọ́sọ́fi, ìmòye, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, èrò àwọn ọ̀mọ̀ràn, èrò àwọn onímọ̀ ọgbọ́n òrí ...
sexta-feira, 14 de setembro de 2018

Par perfeito.

›
Ó wà lára àwọn lọ́gàálọ́gàá.   Ele estava entre seus pares.   Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). Ìpààrọ...
quinta-feira, 13 de setembro de 2018

Teste ancestralidade

›
Àyẹ̀wò ìran baba ńlá àtí ìyá ńlá nípasẹ̀  deoksiribonúkléì kíkan. O lè ṣàwárí ẹ̀yà tàbí ìran tó ti wá.  Teste ancestralidade pelo DNA. Vo...

Coisa estranha

›
Èyí lè ṣe ọ́ ní kàyéfì! Que coisa estranha! Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). Èyí , pron. dem. Este, e...

Colônia

›
Ìdá  ẹ̀k a: À wọn ilẹ̀ àmúsìn Pọ́rtúgàl tẹ́lẹ̀. Categoria: Ex- Colônias de Portugal. Mapa diacrónico do Império Português (1415-1999) ...

Violência policial contra negros segue sem freios no Brasil.

›
                                                    Ẹ̀tanú: olúkúlùkù ẹni tó ń gbé nínú àdúgbò táwọn akúṣẹ̀ẹ́ jẹ́ ọ̀ta tí ó lágbára kan. ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.