Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quinta-feira, 27 de setembro de 2018

Eleição sem Lula é fraude ( 2018)

›
Jìbìtì tó ń pinnu lórí ìdìbòyàn Fraude eleitoral.  É uma intervenção deliberada numa eleição com o propósito de impedir, anular ou ...
quarta-feira, 26 de setembro de 2018

Tucano

›
Orúkọ wo ni ti ẹyẹ nínú àwòrán yìí?  Qual o nome do pássaro dentro desta imagem? Mo fẹ́ mọ̀ orúkọ rẹ̀ nínú èdè Yorùbá. Eu quero saber o ...
segunda-feira, 24 de setembro de 2018

Entrevista

›
                                                      Ìfojúkojú pẹ̀lú àwọn  òǹkọ̀wé dúdú. Entrevista com escritores negros. Àkójọ́...
sábado, 22 de setembro de 2018

Conhecimento

›
Ìmọ̀ ti àgbáyé tipasẹ̀ ti àwọn ìmọ̀lára àti ì mọ̀ t ó ń lò ọgbọ́n ìronú .  Conhecimento do mundo por meio das sensações e conhecimento rac...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.