Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

segunda-feira, 8 de outubro de 2018

Ubuntu

›
Mo wà nítorípe àwa wà.      Eu sou porque nós somos. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). Filọ́sọ́fi Bàn...

Olùkọ́ Orlandes Rosa Farias

›
A dúpẹ́ gan-an lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọmọ ìlú Ìlérí  tí ó dìbò  fún  Adélia,  a rábìnrin mi,  láti sọ Aṣòfin Ìpínlẹ̀.  Agradecemos sincerame...
sexta-feira, 5 de outubro de 2018

Adélia

›
   Olùkọ́ Orlandes  Rosa Farias O lè dìbò fún arábìnrin mi láti di Aṣòfin Ìpínlẹ̀. Você poderá votar em minha irmã para Deputada Esta...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.