Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sexta-feira, 19 de outubro de 2018

Nazismo no Brasil

›
Ọ̀pọ̀ àwọn ará Bràsíl fẹ́ Ìjọba Násì kan  Muitos brasileiros querem um governo nazista. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègb...

Antipetismo

›
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwà kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà wà ní aṣòdì sí ì ṣe  Ẹgbẹ́ ti àwọn Òṣìṣẹ́. Há muito de racismo no antipetismo. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Gloss...
quinta-feira, 18 de outubro de 2018

Pobres que votam no coiso

›
Ó mà múnú ẹni dùn gan-an o láti rí àwọn abẹ́yà-kannáà-lòpọ̀, àwọn aláwọ̀dúdú, àwọn òṣìṣẹ́ tó ń gbowó iṣẹ́, àwọn tálákà, àwọn obìnrin pẹ̀lú ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.