Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sábado, 3 de novembro de 2018

Pensamento preto

›
Jẹ́ kí àwọn ohun tó ń gbéni ró nípa tẹ̀mí máa wà nínú ọkàn rẹ. Encha a mente com pensamentos espiritualmente edificantes. Àkójọ́pọ̀...
sexta-feira, 2 de novembro de 2018

Armas de fogo

›
Ewu ńlá ni ìbọn yíyìn jẹ́ fún àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè wa. A violência com armas de fogo é uma ameaça à saúde pública do nosso país. Àk...

Quilombo urbano

›
                                                        Ìlétò bokẹ́lẹ́ tó wà inú ìlú ńlá . Quilombo urbano. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Gloss...
quinta-feira, 1 de novembro de 2018

Marcos Cesar Pontes

›
Arìnlófurufú kan (láìsí Ọkọ̀ òfurufú) fún Ẹ̀ka Ilé Iṣẹ́ Ètò Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì àti Ìmọ̀ Iṣẹ́ Ẹ̀rọ . Um astronauta (sem nave espacial) para o Mi...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.