Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

terça-feira, 20 de novembro de 2018

Consciência humana

›
A ń dúró dè ẹ̀rí-ọkàn ẹ̀dá ènìyàn. Esperando a consciência humana.  "Toda consciência negra será necessária, enquanto a consciê...
domingo, 18 de novembro de 2018

Carne

›
                    Ẹran (carne, animal) Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). Ẹran-àgùtàn , s. Carneiro,...

Ferramentas

›
Àwọn irinṣẹ́ (ferramentas) Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). Àgbẹ̀dẹ , s. Forja, oficina de ferr...

Gramática

›
  Gírámà (gramática) Substantivo + pronome possessivo. Ilé  ➡️ 🏠  Iléè mi = my house Ìyá  ➡️ 👵 Ìyáà mi = my mother Bàbá  ➡️   ...

Neoliberalismo argentino

›
                          Àwọn ọmọorílẹ̀-èdè Argẹntínà sá lọ sí Bòlífíà ní àwárí ti iṣẹ́. Argentinos fogem para a Bolívia em busca de tra...

Manga.

›
Máńgòrò (Manga) Irvingia gabonensis Extrato de manga africana que consiste nas sementes de uma árvore natural conhecida pelo nome p...

Partes da laranja.

›
Igi ọsàn (laranjeira) Árvore rutácea, de folhagem persistente, cultivada nas regiões quentes, cujo fruto é a laranja, sumarenta e comestív...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.