Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quarta-feira, 21 de novembro de 2018

A presença africana na América antiga

›
Wíwàníhìn-ín ti àwọn ọmọ ilẹ̀ Áfríkà nínú Amẹ́ríkà ayéijọ́un. A presença africana na América antiga. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i ...

Mapa da Necrópole de Gizé

›
Máàpù ti ibi ìsìnkú ìlú pẹ̀lú àwọn Pírámídì Nínlá ti Gísà.  Mapa da Necrópole com as grandes  Pirâmides de Gizé. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀...

Egito

›
Ó jẹ́ ọwọ́ ìrọ̀lẹ́ kíkàmàmà kan ní Íjíbítì. É um fim de tarde espetacular no Egito. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀...
terça-feira, 20 de novembro de 2018

Consciência humana

›
A ń dúró dè ẹ̀rí-ọkàn ẹ̀dá ènìyàn. Esperando a consciência humana.  "Toda consciência negra será necessária, enquanto a consciê...
domingo, 18 de novembro de 2018

Carne

›
                    Ẹran (carne, animal) Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). Ẹran-àgùtàn , s. Carneiro,...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.