Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quinta-feira, 6 de dezembro de 2018

Tubérculos

›
Iṣu ìdí òdòdó ńlá yìí sì fẹ́rẹ̀ẹ́ wọ̀n tó ọgọ́rùn-ún kìlógíráàmù! Este gigante floral tem quase  100 quilos ! Tubérculo   é um órgã...
terça-feira, 4 de dezembro de 2018

A mão do ser humano

›
Fi àtàǹpàkò ọwọ́ kan àti ìka ìlábẹ̀ ọwọ́ kejì fa fọ́nrán okùn ìfọyín náà le tantan. Com o polegar de uma mão e o dedo indicador da outr...
quarta-feira, 28 de novembro de 2018

Dialeto pajubá

›
Èdè àdúgbò tó tí a ń lò láàárín àwọn abẹ́yà-kannáà-lòpọ̀ àtàwọn obìnrin tó ń bá obìnrin lò pọ̀. Dialeto utilizado entre homossexuais e lés...
terça-feira, 27 de novembro de 2018

Cantiga infantil

›
Róndò Róndò Alántakùn (incy wincy spider) Róndò Róndò Alántakùn ó gùn  ọ̀ pá omi, A pequena dona aranha subiu pelo t ubo de queda de...
segunda-feira, 26 de novembro de 2018

Abraço

›
Ìgbámọ́ra kan tí ó ní ẹgbẹ̀rún mẹ́fà ọdún. Um abraço de seis mil anos.  Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário)...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.