Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

terça-feira, 25 de dezembro de 2018

Natal

›
Irú bíi Bàbá Kérésì, lílo igi àfòmọ́ àtàwọn igi Kérésì mí ì, fífúnni lẹ́bùn, títan àbẹ́là, oríṣiríṣi nǹkan ọ̀ṣọ́ tí wọ́n máa ń fi ewé igi ṣ...
sexta-feira, 21 de dezembro de 2018

Feliz natal!

›
Ẹ kú ọdún Kérésìmesì! Ẹ kú iyedún! Ṣùgbọ́n,  ní orúkọ Elédùmarè . . . jọ̀wọ́, má gbàgbé láti fún àwọn  Òrìṣà lókun o. Feliz Natal! Boas F...
quarta-feira, 19 de dezembro de 2018

Cores

›
  ÀWỌN ÀWỌ̀ (CORES): 1. CORES : àwọ ayinrin,  àwọ ojú ọ̀run,  àwọ  búlúù  (cor azul), àwọ (cor lilás), àwọ dúdú (cor preta), àwọ ọsàn, ...
segunda-feira, 17 de dezembro de 2018

Ministra de Bolsonaro Abraça Jesus em Pé de Goiaba

›
 Mínísítà fún àwọn Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn sọ pé ó rí Jésù ń gun  orí  igi góbà kan. Ministra de Direitos Humanos diz ter visto Jesus subindo em u...

Sítio

›
Àwọn ẹranko tó ń gbé nínú oko kéékèèké wa. Animais que vivem em nosso sítio. Abìyé̩ , s. Aquele que possui asas, emplumado, ...
sexta-feira, 14 de dezembro de 2018

Formatura

›
Ayẹyẹ ìkẹ́kọ̀ọ́yege kan tó lárinrin. Uma formatura  extraordinária. . Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário) Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário)...
quarta-feira, 12 de dezembro de 2018

Ètò ẹ̀sọ ara

›
Ètò ẹ̀sọ ara - O sistema nervoso. . Ẹ̀sọ  (nervo). Ètò  ẹ̀sọ t’ogangan  (sistema nervoso central).   Pádi ẹ̀sọ  (célula nervosa , n...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.