Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quinta-feira, 27 de dezembro de 2018

Máquina voadora africana

›
Ẹ̀rọ tó lè fò lófuurufú ti àwọn lárúbáwá nínú sànmánì ojú dúdú. Máquina voadora dos árabes na Idade Média.   Abbas Ibn Firnas, século...

'Èṣù kìí ṣe Sàtánì' (Exu não é Satã)

›
'Èṣù kìí ṣe Sàtánì' (Exu não é Satã)   Àwọn ọmọ Yorùbá tó ń tẹ̀lé ìṣẹ̀ṣe kójọpọ̀ ní àdúgbò Surulere l'Eko láti ṣe àlàyé fún ...
quarta-feira, 26 de dezembro de 2018

Ṣe

›
Ṣe , v. Fazer, agir, causar, desempenhar. Ser. Usado ao lado de advérbio para exibir certa aparência incomum. Imú rẹ̀ ṣe gọn-gọn - O nariz ...

Exu não é satã

›
'Èṣù kìí ṣe Sàtánì' (Exu não é Satã ) Àwọn ọmọ Yorùbá tó ń tẹ̀lé ìṣẹ̀ṣe kójọpọ̀ ní àdúgbò Surulere l'Eko láti ṣe àlàyé fú...
terça-feira, 25 de dezembro de 2018

Natal

›
Irú bíi Bàbá Kérésì, lílo igi àfòmọ́ àtàwọn igi Kérésì mí ì, fífúnni lẹ́bùn, títan àbẹ́là, oríṣiríṣi nǹkan ọ̀ṣọ́ tí wọ́n máa ń fi ewé igi ṣ...
sexta-feira, 21 de dezembro de 2018

Feliz natal!

›
Ẹ kú ọdún Kérésìmesì! Ẹ kú iyedún! Ṣùgbọ́n,  ní orúkọ Elédùmarè . . . jọ̀wọ́, má gbàgbé láti fún àwọn  Òrìṣà lókun o. Feliz Natal! Boas F...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.