Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

domingo, 20 de janeiro de 2019

Oceano Atlântico (Òkun Àtìláńtíìkì)

›
Mò ń wo Òkun Àtìláńtíìkì tí ò jìnnà síbẹ̀. Fiquei olhando para o oceano Atlântico a alguns metros de distância. . Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀...

Cidade de Promissão (Ìlú ìlérí)

›
Ìlú Ìlérí yìí gbóná gan-an ni! Esta cidade de Promissão é muito quente! Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário...

Àwọn òdòdó inú igbó (flores silvestres)

›
Nígbà ẹ̀ẹ̀rùn, ńṣe làwọn àfonífojì àti ilẹ̀ eléwéko tútù máa ń dà bíi kápẹ́ẹ̀tì tó ní oríṣiríṣi òdòdó nínú. No verão, os vales e as campi...
sexta-feira, 18 de janeiro de 2019

Oxum

›
                            Ọ̀ṣùn  (Oxum)   Divindade das águas dos rios que fertilizam o solo e que dá nome a um dos rios que corre na r...
quarta-feira, 16 de janeiro de 2019

Cacho de bananas

›
Pádi ọ̀gẹ̀dẹ̀ (cacho de bananas). Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). Abá , s. Espécie  de esteira ou a...

Primeiro Campeonato de Surf na Terra Plana

›
Ìdíje Àkọ́kọ́ ti Fífi pátákó sáré lórí omi ní Ojú ilẹ̀ ayé tẹ́ pẹrẹsẹ. 1º Campeonato de Surf na Terra Plana. . Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.