Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

terça-feira, 5 de março de 2019

Filosofia

›
Filọ́sọ́fi, ìmòye, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, èrò àwọn ọ̀mọ̀ràn, èrò àwọn onímọ̀ ọgbọ́n òrí ( filosofia, rekhet ) 1. É uma reflexão crítica a respe...
segunda-feira, 4 de março de 2019

Grito de guerra.

›
Kẹ́ ẹ wá fun àwọn ìwo náà kíkan-kíkan, kí gbogbo yín sì ké ní ohùn rara. Daí, toquem alto as buzinas, todos dando um grande grito de guerr...

Ìlù Ọba Dé Mi.

›
                                                    Ìlù Ọba  Dé Mi. O tambor do rei veio para mim. Ìlù Ọba Dé Mi - Àwọn obìnrin tí ńṣir...

Ilẹ̀ ọbalúayé Ghánà (Império do Gana)

›
Ilẹ̀ ọbalúayé Ghánà . Império do Gana, Reino do Gana ou Império de Uagadu. Wọ́n yọ̀ǹda ara wọn tinútinú láti sọ̀rọ̀ nípa Ilẹ̀ ọbalúayé ...

Lábẹ́ igi òroǹbó (Sob a laranjeira)

›
  Orin ìdárayá - Lábẹ́ igi òrombó. Cantiga de alegria - Sob a laranjeira. Lábẹ́ igi òroǹbó Níbẹ̀ la gbé ńṣeré wa Inú wa dùn, ara wa...
domingo, 3 de março de 2019

Ìgbà ayẹyẹ ìlú (carnaval)

›
Ìlù Ọba  Dé Mi. O tambor do rei veio para mim. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). Ìlú , s. Cidade, terr...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.