Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quinta-feira, 7 de março de 2019

Presidente Bolsonaro posta vídeo de pornografia gay no Twitter

›
Ààrẹ Bolsonaro fi fídíò ìṣekúṣe pẹ̀lú àwọn o̩kùnrin níhòòhò lórí twíítà àti  ìyàlẹ́nu gbogbo  ènìyàn. Presidente Bolsonaro posta vídeo d...
quarta-feira, 6 de março de 2019

O diabo venceu, sim!

›
Òótọ́ ọ̀rọ̀ ni ilé ijó sáńbà àti ẹlẹ́kọ̀ọ́ ìsìn sọ pé:  Sátánì ṣẹ́gun, bẹ́ẹ̀ o! De fato, Escola de samba e teólogo têm razão ao dizer: o ...
terça-feira, 5 de março de 2019

Filosofia

›
Filọ́sọ́fi, ìmòye, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, èrò àwọn ọ̀mọ̀ràn, èrò àwọn onímọ̀ ọgbọ́n òrí ( filosofia, rekhet ) 1. É uma reflexão crítica a respe...
segunda-feira, 4 de março de 2019

Grito de guerra.

›
Kẹ́ ẹ wá fun àwọn ìwo náà kíkan-kíkan, kí gbogbo yín sì ké ní ohùn rara. Daí, toquem alto as buzinas, todos dando um grande grito de guerr...

Ìlù Ọba Dé Mi.

›
                                                    Ìlù Ọba  Dé Mi. O tambor do rei veio para mim. Ìlù Ọba Dé Mi - Àwọn obìnrin tí ńṣir...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.