Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quarta-feira, 19 de junho de 2019

OVNI filmado em Promissão.

›
UFO tó wà nínú fídíò ní Ìlú ìlérí. OVNI filmado em Promissão. Fídíò tí Olùkọ́ Orlandes ti mú jáde - V ídeo produzido pelo Professor ...

Mandruvá

›
Bí kòkòrò wùkúwùkú, eéṣú, àti aáyán ṣe bo ilẹ̀ náà lohun tí Jóẹ́lì rí nínú ìran. Em visão, Joel viu a invasão da lagarta, do gafanhoto e d...
terça-feira, 18 de junho de 2019

Titanic

›
Ó ṣeé ṣe káwọn tó ṣe ọk ọ̀  Tìtáníìkì àtàwọn èrò tó wọ̀ ọ́ fi tọkàntọkàn gbà pé ọkọ̀ òkun ńlá náà ò lè rì láé. Os construtores e os passag...

Vagas de emprego.

›
Àwọn ilé iṣẹ́ bá polówó  pé àwọn ń wá òṣìṣẹ́.  Empresas dizem que estão procurando trabalhadores. Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário) Àkójọ́...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.