Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sexta-feira, 5 de julho de 2019

Documentos

›
Àwọn àkọsílẹ̀ ara ẹni, àwọn àkọsílẹ̀ gbogbo gbòò, tàbí lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì. Documentos pessoais, documentos públicos ou na Internet. Àkój...

Cadastro Ambiental Rural

›
Ìforúkọsílẹ̀ Àyíká Tó Wà Nínú Oko. Cadastro Ambiental Rural. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Para mais informações: http://www....
terça-feira, 2 de julho de 2019

Afrocentricidade

›
Àwọn àyọkà kan máa ń ṣí àǹfààní sílẹ̀ fún kíkẹ́kọ̀ọ́ jinlẹ̀ àti ṣíṣe àṣàrò, tí yóò sì wá jẹ́ kéèyàn ní ìjìnlẹ̀ òye. Alguns textos dão am...
segunda-feira, 1 de julho de 2019

Está ventando (afẹ́fẹ́ ń fẹ́)

›
Afẹ́fẹ́ ń fẹ́ àwọn ẹyẹ ò lè ba sórí igi. Está ventando, os passarinhos não podem pousar na árvore. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ì...

Deus-sol Rá.

›
Ọlọrun Ráà ti Íjíbítì  jí mi. O deus Rá do Egito ( Kemet)  me despertou. . Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulá...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.